Ọwọ NDLEA tẹ awọn meji to gbe kokeeni, idi marunlelọgọjọ (165) ni wọn ya

Ọrẹoluwa Adedeji Kilogiraamu oogun oloro ti wọn n pe ni kokeeni ti idi rẹ jẹ marunlelọgọjọ…

Eeyan mẹrin ku, mẹtala fara pa, ninu ijamba ọkọ l’Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ko din leeyan mẹrin ti wọn ku, nigba tawọn ero mẹtala tun fara…

Ọwọ ọlọpaa tẹ ṣọja atawọn meji mi-in to ji akẹkọọ yunifasiti gbe l’Ekiti Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti…

Lẹyin ọjọ kẹta ti wọn paayan marundinlogoji, awọn agbebọn tun fẹmi aadọta eeyan ṣofo ni Kaduna

Gbenga Amos  Niṣe lẹjẹ n ṣan bii omi lafẹmọju ọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kẹẹẹdọgbọn, oṣu Kẹta…

Akọlukọgba waye nibi ipade gbogbogboo APC, alaboyun atawọn mẹẹẹdọgbọn mi-in fara pa

Jọkẹ Amọri Awọn eeyan to le diẹ ni mẹẹẹdọgbọn, ninu eyi ti alaboyun wa ninu wọn…

Oludamọran Fayẹmi lori eto oṣelu kọwe fipo silẹ, o darapọ mo ẹgbẹ SDP

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Oludamọran agba lori ọrọ to jẹ mọ eto idibo fun Gomina Kayọde Fayẹmi…

Nitori eto idibo ipinlẹ Ekiti, Ọṣun Akintoye wọ ajọ INEC lọ sile-ẹjọ

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ẹgbẹ Ilana Ọmọ Oodua nile loko, ti Ọjọgbọn Banji Akintoye jẹ adari rẹ,…

Eyi ni bawọn ẹlẹgbẹ okunkun ṣe pa Tommy l’Abẹokuta

Gbenga Amos, Abẹokuta Titi di ba a ṣe n sọ yii, inu ibẹrubojo lawọn olugbe agbegbe…

Ọlọpaa to n halẹ m’awọn ti mọto wọn ni gilaasi tintẹẹdi l’Ekoo ti n kawọ pọnyin rojọ

Faith Adebọla, Eko  Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ti mu Inspẹkitọ Dele Reuben, ọlọpaa to fooro ẹmi…

Chidinma ṣe pati daran, wọn sọ ọ sẹwọn ọdun meji tori bẹntiroolu to ha fawọn alejo ẹ

Faith Adebọla, Eko  Ṣẹ ẹ ranti obinrin alafẹ ilu Eko, Chidinma Pearl Ogbulu, tọrọ pati rẹ…

Alele-Williams, obinrin akọkọ to jẹ ọga agba fasiti ni Naijiria, jade laye

Faith Adebọla  Abilekọ Grace Alele-Williams, obinrin to fitan balẹ lọdun 1985 gẹgẹ bii ọga agba fasiti…