Sifu difẹnsi ti mu Ismail at’ọrẹ ẹ to fọ ṣọọbu pẹlu Jẹlili to ra ẹru ole lọwọ wọn l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Ọṣogbo Ọwọ ajọ sifu difẹnsi ipinlẹ Ọṣun ti tẹ awọn ọdọkunrin meji; Oyejọla Ismail, to…

A o ni i bẹ Buhari nitori Sunday Igboho o, tori ko dẹṣẹ kankan-Afẹnifẹre

Faith Adebọla, Eko Ẹgbẹ Afẹnifẹre to n ja fun ominira Yoruba, ti sọ pe awọn o…

Oju ti pọn awọn Fulani ju ni Naijiria yii, afi ka tọju wọn atawọn maaluu wọn-Sheikh Gumi

Faith Adebọla “O da bii ẹni pe ijọba apapọ ti juwọ silẹ fawọn to n fojoojumọ…

Ọlọpaa bẹrẹ iwadii lori iku tọkọ-taya ti wọn ba oku wọn ninu ile l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ọlọpaa ni awọn ti bẹrẹ iwadii lori iṣẹlẹ awọn oku mẹta ti…

Baba yii ṣa ẹgbọn ẹ pa ni Mowe nitori ilẹ mọlẹbi

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ẹni ọdun mejidinlọgọrin ( 78) ni baba ti ẹ n wo yii, Mọshood…

‘Ọdọ iya iyawo mi ni mo maa n tọju ibọn ta a fi n ṣiṣẹ ijinigbe ati ole jija si’

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Johnson Apotire, Jimọh Dele, ti wọn tun maa n pe ni Dele Petim,…

Ẹ wo Fatima, obinrin to n gbe nnkan ija oloro fawọn agbebọn ninu igbo

Faith Adebọla  Beeyan ba kọkọ wo bi obinrin ẹni ọgbọn ọdun yii ṣe da hijaabu bori…

Loootọ ni Tinubu bẹbẹ fun atilẹyin mi lati di aarẹ lọdun 2023 ni- Yakassai

Agba oloṣelu apa Oke-Ọya ilẹ wa kan, to tun jẹ agba ẹgbẹ Arewa Consultative Forum, Alaaji…

Akẹkọọ to ba tapa sofin yoo balẹ sile awọn ọmọ alaigbọran- Arigbabu

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Kọmiṣanna eto ẹkọ, Sayẹnsi ati Imọ ẹrọ nipinlẹ Ogun, Ọjọgbọn Abayọmi Arigbabu, ti…

Ile-ẹjọ kede awọn agbebọn to n paayan kiri bii afẹmiṣofo 

Faith Adebọla  Ile-ẹjọ giga apapọ kan niluu Abuja ti kede lọjọ Ẹti, Furaidee yii, pe ko…

Awọn oṣere fi atilẹyin han fun Tinubu lati di aarẹ ni 2023

Adefunkẹ Adebiyi Ọkunrin ọmọ Ibo kan to maa n ṣe tiata lede oyinbo ati ede Ibo,…