Iya Ṣanko Raṣidi onifuji ti ku o!

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Iya to bi ọdọmọkunrin onifuji nni, Rasheed Atanda tawọn eeyan mọ si Shanko…

Ẹ wo Gbenga, ọkan ninu awọn adigunjale to ja ọkọ bọọsi awọn ọmọ ileewe gba l’Ọba-Ile

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkan ninu awọn ọmọ ẹgbẹ adigunjale to ja bọọsi awọn ọmọ ileewe kan…

Eyi ni bi awọn agbebọ ṣe pa awọn ara Ikarẹ-Akoko mejilelogun ti wọn n bọ lati ipinlẹ Bauchi

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Eeyan mejila la gbọ pe ọwọ ti tẹ lori iṣẹlẹ iṣekupani to waye…

Awọn tọọgi ya bo sẹkiteriati APC l’Ọṣun, alubami ni wọn lu awọn ọmọ ẹgbẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọrọ di bo o lọ o ya lọna lonii ni olu-ile ẹgbẹ oṣelu…

Wọn ka Sunday mọbi to ti n jale l’Ekoo, ibọn meji loun nikan n lo

Faith Adebọla, Eko Ko jọ pe afurasi ọdaran, Sunday Akpa, tọwọ awọn agbofinro tẹ lagbegbe Iba,…

Akẹkọọ TASUED para ẹ, nitori o kuna ninu idanwo aṣekagba

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Titi dasiko yii lawọn eeyan ṣi n sọrọ aro nipa ọmọbinrin kan, Oshọkọya…

Tirela wo lu ọkọ ayọkẹlẹ l’Orimẹrunmu, lo ba tẹ dẹrẹba pa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Tirela kan ti gaasi wa ninu rẹ, padanu ijanu ẹ laaarọ ọjọ Satide,…

Lai bọwọ fofin Korona, ero rẹpẹtẹ kopa ninu ọdun Ọṣun Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Kaakiri awọn ipinlẹ to wa lorileede yii lawọn eeyan ti tu yaaya wọnu…

Ileeṣẹ ọlọpaa ti le Sajẹnti Adamu to yinbọn pa Ọmọọba l’Oṣogbo lẹnu iṣẹ

Ileeṣẹ ọlọpaa ti le Sajẹnti Adamu to yinbọn pa Ọmọọba pa Ọmọọba l@fun igbẹjọ ati ijiya…

Laarin ọsẹ meji, eeyan meje ni arun Koronafairọọsi ti pa l’Ọṣun – Ẹgbẹmọde

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Pẹlu bi ajakalẹ arun Koronafairọọsi ṣe n ṣoro bii agbọn kaakiri, o ti…

‘Wọn de mi lọwọ lẹsẹ fun ọjọ meji gbako ninu ojo, mi o gbadura iru iriri bẹẹ f’ọtaa mi’

Faith Adebọla “Wọn foju mi ri mabo nigba ti mo wa lakata wọn, wọn ṣe mi…