Nibi ti wọn ti n le awọn onifayawọ, aṣọbode yinbọn pa eeyan marun-un niluu Isẹyin

Eeyan marun-un lawọn aṣọbode ilẹ wa tun yinbọn pa ni Ọjọbọ, Tosidee, ọsẹ yii, niluu Isẹyin,…

Agba ofifo lasan lawọn gomina to ṣofin pe ki wọn yee fi maaluu jẹko ni gbangba-Akowe Miyetti Allah

Faith Adebọla Boya lawọn gomina ipinlẹ mẹtadinlogun ti wọn fori kori nipade apero nla kan ti…

Ajagun-fẹyinti Joṣhua Dongoyaro ti dagbere faye

Faith Adebọla Ṣe ẹ ranti ọgagun kan to awọn ọmọ orileede yii sọrọ lori redio ati…

Abiọdun ati Ọpẹyẹmi fibọn gba ọkada ni Sango, nibi ti wọn ti n sa lọ lọwọ ọlọpaa ti tẹ wọn

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ni nnkan bii aago mẹjọ alẹ ọjọ kẹwaa, oṣu karun-un yii, ni olobo…

 Miliọnu lọna ọgbọn naira lawọn to ji pasitọ ijọ Deeper Life l’Akurẹ n beere fun

  Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn agbebọn to ji pasitọ ijọ Deeer Life gbe ninu sọọsi rẹ to…

Awọn Fulani afẹmiṣofo ti yi ilẹ Yoruba po o, wọn fẹẹ kọ lu awọn sọọṣi ati mọṣalaasi-Ọjọgbọn Akintoye

Faith Adebọla                             “Mo fi tọwọtọwọ rọ awọn gomina ilẹ Yoruba lati fori kori bayii, mo si…

A ko ni i fi Baba Ijẹṣa silẹ, ahamọ wa lo maa gba de kootu – Kọmiṣanna ọlọpaa Eko

Faith Adebọla Ileeṣẹ ọlọpaa Eko ti sọ fun gbajugbaja oṣere tiata ilẹ wa kan, Yọmi Fabiyi,…

O ma ṣe o! O kọla ti Reuben yoo re’lu oyinbo ni wọn ṣa oun ati iya rẹ pa sinu oko Alapata, l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti bẹrẹ iwadii lori awọn ti wọn ṣa obinrin…

Olowu Kuta rọ awọn Musulumi: Ẹ jawọ ninu awọn iwa ti ko fogo f’Ọlọrun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Olowu Kuta, nipinlẹ Ọṣun, Ọba Hameed Oyelude Makama, ti rọ awọn Musulumi kaakiri…

 O ma ṣe o, akẹkọọ Fasiti Adekunle Ajasin gbe majele jẹ l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkan ninu awọn akẹkọọ Fasiti Adekunle Ajasin to wa niluu Akungba Akoko, Fẹranmi…

Ijọba ipinlẹ Ekiti fun awọn ẹlẹwọn mejila lominira 

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ninu eto iforiji ti ijọba ipinlẹ Ekiti gbe kalẹ lati ṣami ayẹyẹ ọdun…