Nibi ti Iya Maria ti n ṣaajo ọmọ ati ọmọọmọ ẹ tawọn ajinigbe fẹẹ gbe ni wọn ti yinbọn pa a n’Ijohun

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Ara ọmọ to ta iya kan ti wọn n pe ni Iya Maria, lagbegbe Ijohun,…

Nitori ọdun iṣẹmbaye ti wọn fẹẹ ṣe, Deji ti gbogbo ọja pa l’Akurẹ fun ọjọ meji

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ.  Deji tilu Akurẹ, Ọba Aladetoyinbo Aladelusi, ti paṣẹ pe ki gbogbo ọja atawọn…

Awọn janduku ya wọ teṣan ọlọpaa n’Ibadan, wọn yinbọn pa kọburu kan

Ọlawale Ajao, Ibadan Aṣa fi òròmọdìẹ silẹ, àkùkọ atawọn àgbébọ̀ adiẹ nla nla lo ku to…

Fidio: Ọkan ninu awọn baalẹ Akinyẹle, nibi ti Sunday ti n ṣa awọn eeyan pa, ti b’ALAROYE sọrọ

Eeyan marun-un ku ni marosẹ Eko s’Ibadan, ere asapajude lo fa a

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ni nnkan bii aago mẹsan-aabọ aarọ Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, leeyan marun-un (ọkunrin…

Wọn ni Isaac mu nnkan ọmọkunrin Ṣeyi l’Ọta, ni ‘kinni’ ẹ ko ba ṣiṣẹ mọ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Titi di asiko ti a n kọ iroyin yii, nnkan ọmọkunrin Ṣeyi Azeez,…

Aluchi ran ole si araale ẹ ni Lusada, miliọnu mẹta aabọ ni wọn gbe lọ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ni Eleweeran, l’Abẹokuta, lawọn ọlọpaa ti ṣafihan ọkunrin kan, Aluchi Emmanuel, pẹlu ẹni…

Nitori ipolongo to ṣe fun Fayẹmi, awọn aṣofin fun alaga ijọba ibilẹ Ikẹrẹ niwee gbele-ẹ

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ile-igbimọ aṣofin ipinlẹ Ekiti ti fun alaga ijọba ibilẹ Ikẹrẹ, Ọnarebu Fẹmi Ayọdele,…

Eyi ni bawọn aṣaaju Hausa-Fulani ṣe ba Naijiria yii jẹ (13)

Gẹgẹ bii ileri ti mo ṣe lori ọrọ ti a n ba bọ latẹyin, mo sọ…

Eeyan mẹrinla mi-in tun ko Korona ni Ọsibitu Ọlabisi Ọnabanjọ, ni wọn ba ti ẹka ayẹwo ibẹ pa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Awọn alaṣẹ Ọsibitu Ọlabisi Ọnabanjọ (OOUTH), ni Ṣagamu, ti tilẹkun ẹka to n…

Ọwọ tẹ wọn o: awọn to n fi ọkada ja foonu gba nIlọrin

Stephen Ajagbe, Ilọrin Ọwọ palaba awọn ọdaran meji, Adam Taofeek ati Alabẹrẹ Adam, ti wọn maa…