Ileeṣẹ agunbanirọ fiya jẹ mọkanla ninu wọn to n sa lẹnu iṣẹ

 Ọlawale Ajao, Ibadan  Yatọ si awọn meji to j’Ọlọrun nipe lasiko ti wọn n ṣiṣẹ sin…

Iru ki waa leleyii! Sherifat n mura idanwo Wayẹẹki lọwọ lo fi binu para ẹ n’Ikorodu

 Faith Adebọla Orin wo la fẹẹ kọ si gbẹdu lọrọ da pẹlu bi ibanujẹ ati ọgbẹ…

O TAN! ARUN KORONA TI MU MINISITA BUHARI O

Ọkan ninu awọn minisita ti wọn n ba Aarẹ Muhamadu Buhari ṣiṣẹ ninu jjọba rẹ yii…

Nilẹ Zambia, eeyan mejidinlọgbọn ko Koronafairọọsi ni kilọọbu kan

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ṣe lawọn alaṣẹ liigi ilẹ Zambia to yẹ ko bẹrẹ lọjọ Abamẹta, Satide,…

‘A FẸẸ MỌ IKU TO PA ỌMỌ WA O,’ AWỌN YORUBA KOGI BINU

Ọrọ iku to pa ọmọọbinrin afẹronpileeni-jagun, Tolulọpẹ Arotile, ko ti i tan nilẹ rara, nitori iruju…

Oṣiṣẹ wa to ba gbowo ẹyin atẹni to fun un yoo foju bale-ẹjọ-FRSC

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ajọ ẹṣọ alaabo oju popo (FRSC), ti kede pe eyikeyii ninu awọn oṣiṣẹ…

KO SAAYE ỌDUN IBILẸ KANKAN NI GBOGBO EKITI BAYII O

Gbogbo ọdun ibilẹ pata ni wọn ti fi ofin de ni ipinlẹ Ekiti bayii o. Bo…

“Ẹ MA JẸ KAWỌN ỌMỌLEEWE WỌLE O, Ẹ JẸ KO D’ỌDUN TO N BỌ”

Ẹgbẹ awon olukọ ni yunifasiti gbogbo nilẹ yii ti wọn n pe ni ASUU ti sọ…

Aṣiṣe nla ni bi mo ṣe fi Agbọọla ṣe igbakeji mi – Akeredolu

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Asiṣe nla gbaa lo jẹ fun mi lori bi mo ṣe yan Agboọla…

Kọmiṣanna eto ẹkọ ti ko si nipinlẹ Ogun n fa wa sẹyin-Ẹgbẹ Akẹkọọ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta  Apapọ ẹgbẹ akẹkọọ nipinlẹ Ogun, ‘National Association of Ogun State Students’ (NAOSS), ti fi…

Korona: Ijọba ko aadọta eeyan nile-ijo taka-sufee n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin Fun pe wọn tapa sofin to de ṣiṣi ile-ijo lasiko ajakalẹ arun Korona,…