Ojoojumọ lọkọ mi maa n lu mi nilukilu nitori ibalopọ, mi o fẹ ẹ mọ – Esther

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Kootu kọkọ-kọkọ to wa lagbegbe Oke-Ẹda, l’Akurẹ, ni obinrin ẹni ọdun marundinlogoji kan, Esther…

Awọn oṣiṣẹ ijọba Ekiti fẹẹ ba Fayẹmi k’ẹsẹ bọ ṣokoto ija o

Gbogbo ẹgbẹ awọn oṣịṣẹ patapata ti para pọ ni ipinlẹ Ekiti bayii o, wọn si ni…

O ga o: terela Dangote tun g’ori ọlọkada l’Agọ-Iwoye, o pa a patapata

Laaarọ yii ni. Ere buruku ni wọn ni mọto terela Dangote naa n ba bọ, o…

O ṣẹlẹ! Akeredolu sọrẹnda

  Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ   Lẹyin bii ọdun mẹta o le to ti gori aleefa, Gomina…

‘Nitori owo ni mo ṣe bẹ ọrẹ mi lori o!’, Moses lo sọ bẹẹ

Afi ki eeyan maa ṣọra ko too finu han fẹni kan. Awọn ọrẹ a maa ṣeku…

O MA ṢE O: AWỌN ỌLỌPAA MẸTA KU S’OD0 NILUU ỌYỌ

Awọn ọlọpaa mẹta kan ti ba omi lọ nilu Ọyọ Alaafin o. Wọn ko somi, wọn…

Ẹ woju wọn, awọn ni wọn pa Barakat, ti wọn tun pa alaboyun atawọn mi-in l’Akinyẹle, n’Ibadan

  Titi di ba a ṣe n sọ yii ni gbogbo awọn to wa nibi tawọn…

Ipade alaafia awọn oludije sipo gomina ẹgbẹ APC Ondo fori sanpọn

  Iyiade Oluṣẹyẹ, Akurẹ Afaimọ ki fa-a-ka-ja-a to n fojoojumọ ṣẹlẹ ninu ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ…

Nitori bi korona ṣe pa ọkan ninu wọn, awọn aṣofin Eko bẹrẹ ayẹwo

  Latari aṣẹ tileegbimọ aṣofin Eko  pa pa pe ki gbogbo awọn ọmọ ile aṣofin naa,…

Nibo lẹyin n gbe, nibo lẹyin wa: Nigba t’Abiọla atawọn eeyan rẹ kọju ija si Awolọwọ ni 1979

*Idi abajọ ree o (2) Afi bii ẹni pe awọn eeyan naa ti ni Oloye Ọbafẹmi…

Eyi ni bawọn aṣaaju Hausa-Fulani ṣe ba Naijiria yii jẹ (9)

Mo n tẹnu mọ ipade ofin ilẹ wa ti wọn ṣe ni ọdun 1950 yii pupọ,…