Ajalu buruku! Oṣere tiata mi-in tun ku lojiji

Faith Adebọla Ọkan ninu awọn oṣere tiata ilẹ wa to ṣẹṣẹ n goke agba bọ, Adejumọkẹ…

Ti Naijiria yoo ba goke agba, iṣẹ wa lọwọ adari atawọn ọmọlẹyin – Imaamu agba ilu Ọffa

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Imaamu Agba ilu Ọffa, Sheikh Muydeen Saliman, ti ke si awọn adari lorileede…

Wọn ti yọ Igbakeji gomina Edo, Philip Shuaib, nipo

Faith Adebọla  Ileegbimọ aṣofin ipinlẹ Edo ti fountẹ jan abajade iwadii igbimọ to gbọ awọn ẹsun…

Ọwọ tẹ ayederu ọmọ ogun oju omi to n lu awọn eeyan ni jibiti l’Ekoo

Adewale Adeoye Ayederu ọmọ ogun oju omi kan,  Muhammad Tunde, ti wọn ti gbaṣẹ lọwọ rẹ lati ọdun 2000, nitori iwa palapala to hu,…

Ẹjẹ eeyan lawọn eleyii rọ sinu kẹẹgi ti wọn ba lọwọ wọn

Adewale Adeoye Bọrọ tawọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kaduna n sọ ba jẹ ootọ, ọsẹ yii ni wọn maa foju awọn afurasi ọdaran ikọ ẹlẹni mẹsan-an…

Ewe sunko! Oogun afẹẹri ti Ọlalekan ṣe lati gbe egboogi oloro kọja ni ẹẹpọọtu ko ṣiṣẹ

Faith Adebọla  Niṣe ni ọkunrin afurasi ọdaran yii, Imran Taofeek Ọlalekan, ẹni ọdun mẹrinlelogoji (44), lanu…

Aadọta miliọnu lawọn ajinigbe to ji akẹkọọ Fasiti Taraba meji n beere fun

Adewale Adeoye Miliọnu lọna aadọta Naira (N50M) lawọn ajinigbe kan ti wọn ji akẹkọọ ileewe Fasiti Taraba ‘Federal University’, to wa lagbegbe Wukari, nipinlẹ Taraba, n beere…

Lẹyin ti baale ile yii pa iyawo ẹ tan loun naa gbe majele jẹ

Adewale Adeoye Ha-in lọrọ oṣiṣẹ banki kan, Oloogbe Mike Illishebo, ẹni ọdun mẹrinlelogoji, to pa iyawo rẹ,  Valeria Franco, ẹni ọdun marundinlogoji, ṣi n…

Ojo nla ṣọṣẹ ni Poli Ekiti, ọpọlọpọ nnkan lo bajẹ

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Kayeefi nla lo jẹ fun gbogbo eeyan ipinlẹ Ekiti l’Ọjọbọ, Wẹsidee, ọjọ kẹta,…

Ọpọlọpọ egboogi oloro ti ọmọkunrin yii fẹẹ gbe sọda siluu oyinbo lo ti ya jade lakata NDLEA

Monisọla Saka Ọwọ ajọ to n gbogun ti tita, rira ati lilo egboogi oloro nilokulo lorilẹ-ede…

Ibọn onike lawọn eleyii fi n jale tọwọ fi tẹ wọn

Adewale Adeoye Ọdọ awọn ọlọpaa agbegbe Isọkoko, ni Agege, nipinlẹ Eko, lawọn gende meji kan, Kyari Idris, ẹni ogun ọdun, ati Abubarkar Salisu, ẹni ọdun mejidinlogun wa. Ẹsun ti wọn…