Yoruba World Centre fẹẹ ṣeto nla fun Olubadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Gbogbo eto lo ti to bayii lori eto nla ti awọn Yoruba World…

APC fa ọjọ idibo abẹle wọn sẹyin, ọjọ kọkandinlọgbọn, oṣu yii, ni wọn yoo yan oludije funpo aarẹ

Monisọla Saka L’Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii, ni Akọwe ipolongo fun ẹgbẹ oṣelu APC, Felix Morka, kede…

Ọwọ tẹ Ọlamide atawọn ọrẹ ẹ, oni POS ni wọn lu ni jibiti n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ileeṣẹ ọlọpaa, ẹka ti ipinlẹ Kwara, ti mu awọn afurasi mẹta kan, Ọlamide…

Nitori to ni oun yoo fopin si eto aabo ni Borno ati Yobe, PDP Ekiti sọrọ si Fayẹmi

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ẹgbẹ PDPipinlẹ Ekiti ti yẹgẹ ẹnu si gomina ipinlẹ Ekiti, Dokita Kayọde Fayẹmi,…

Sanwo-Olu fofin de ọkada nijọba ibilẹ mẹfa l’Ekoo

Faith Adebọla O deewọ bayii fawọn to n fi ọkada gbe ero, tabi fi i ṣe…

Amọtẹkun tẹ Afeez ati ọrẹ rẹ ti wọn fipa ba ọmọbinrin to n ṣe nnkan oṣu lo pọ n’Iwoo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn ọdọmọkunrin meji kan, Adegoroye Afeez, ẹni ọdun mẹrinlelogun ati Ọlamilekan Elijah, ẹni…

Ko sọmọ ẹgbẹ PDP to le figagbaga pẹlu mi lọdun 2023 – Tinubu

Faith Adebọla Ondije fun ipo aarẹ lẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC, ati adari apapọ ẹgbẹ…

Ọṣun 2022: Ile-ẹjọ ni Ademọla Adeleke ni oludije fun ẹgbẹ oṣelu PDP

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ile-ẹjọ giga ijọba apapọ to wa niluu Oṣogbo, ti fagi le ẹjọ ti…

Awọn obi pe ọmọ wọn atiyawo ẹ lẹjọ, tori wọn o rọmọ bi lẹyin ọdun mẹfa igbeyawo wọn

Bo ba jẹ ori tẹlifiṣan lọrọ ọhun ti ṣẹlẹ, awada kẹrikẹri leeyan iba ro pe wọn…

Buhari yan ọga agba tuntun fun ileeṣẹ agunbanirọ

Faith Adebọla Olori orileede wa, Ajagun-fẹyinti Muhammadu Buhari, ti yan ọga agba tuntun fun ileeṣẹ awọn…

Akẹkọọ Poli Ibadan loogun amarale, lo ba ku lẹyin ibalopọ pẹlu ọrẹbinrin ẹ n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Ti wọn ba n ṣadura pe ki Ọlọrun ma ṣe jẹ ka ba…