Lanlọọdu ati getimaanu pa ọmọọdun mẹrin, wọn yọ ẹya ara ẹ lati fi ṣoogun owo

Faith Adebọla Diẹ lo ku kawọn araalu tinu n bi dana sun baba getimaanu kan nigba…

Nitori ti wọn dari alaisan lọ si ọsibitu aladaani, ijọba da dokita ati nọọsi duro nipinlẹ Ọyọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori ti wọn dari awọn alaisan lọ sileewosan aladaani, ijọba ipinlẹ Ọyọ ti…

Nibi ti Ṣẹgun atawọn ọrẹ ẹ ti n ṣepade oko ole ti wọn fẹẹ lọ lawọn ọlọpaa ka wọn mọ

Gbenga Amos, Abẹokuta Ṣẹgun Azeez, afurasi adigunjale ẹni ọdun mẹrindinlọgbọn, tọwọ awọn ọlọpaa ẹka ileeṣẹ wọn…

Ileelẹ ti wọn fẹẹ sọ di alaja mẹta wo l’Ekoo, oku mẹrin ni wọn hu jade

Ileelẹ ti wọn fẹẹ sọ di alaja mẹta wo l’Ekoo, oku mẹrin ni wọn hu jade…

Awọn ọdọ tun dana sunle, ṣọọbu ni Bauchi, wọn lọmọbinrin kan sọrọ odi si Islam

Ọrẹoluwa Adedeji Wahala mi-in tun ṣẹlẹ ni ilu kan ti wọn n pe ni Katangan-Waji, ni…

Arẹmu Afọlayan ṣepe nla fawọn oloṣelu, o lawọn lo ba Naijiria jẹ

Faith Adebọla Gbajugbaja oṣere tiata ilẹ wa kan, Arẹmu Afọlayan, ti wọn epe nla fawọn oloṣelu…

Ijọba gbọdọ gba awọn ọlọpaa si i ti a ba fẹ ki wahala eto aabo dopin lorileede yii – Ọsinbajo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Igbakeji Aarẹ orileede yii, Ọjọgbọn Yẹmi Ọsinbajo, ti sọ pe ọkan pataki lara…

Ẹ jẹ ka fọwọsowọpọ pẹlu ẹnikẹni to ba wọle ibo abẹle APC-Ọṣinbajo

Monisọla Saka Igbakeji Aarẹ ilẹ yii, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo, ti sọ pe, pẹlu iye awọn eeyan…

Oriṣiiriṣii nnkan ija oloro ni wọn n tọju sinu ọja Alaba Rago-Ijọba Eko

Faith Adebọla, Eko Ijọba ipinlẹ Eko ni awọn ti pari eto lori atunṣe ọja to gbajumọ…

Nitori obinrin, Danladi gun ọrẹ rẹ pa l’Ode-Aye

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkunrin ẹni ọdun mejilelogun kan, Money Danladi, ni wọn ti fẹsun kan pe…

Lẹyin ọdun mẹta ti tẹnanti tilẹkun ile pa, adajọ ni ki lanlọọdu lọọ ja a n’Ilọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, ni ile-ẹjọ Majisreeti kan niluu Ilọrin paṣẹ ki lanlọọdu…