Lọdun 2023, iha Oke-Ọya lo ṣi maa bọ sipo aarẹ – Gomina Bauchi

Faith Adebọla  Gomina ipinlẹ Bauchi, Alaaji Bala Mohammed, ti sọ pe bi agbara ba maa kuro…

Losiriọsi bọọsi gbina lori ere l’Akoko

Iyiade Oluṣẹyẹ, Akurẹ Ori lo ko awọn ero inu ọkọ bọọsi lọsiriọsi kan yọ laaarọ ọjọ…

 Lẹyin tawọn Fulani darandaran fipa ba Roseline lo pọ tan ni wọn pa a sinu oko n’Igbọkọda

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọgọọrọ Hausa atawọn Fulani darandaran to wa lagbegbe Igbọkọda, nijọba ibilẹ Ilajẹ, ni…

Awọn oloye Ibadan ti tun ni ki lọọya gbe iwe ẹjọ kuro ni kootu, wọn lawọn o ṣẹjọ mọ

Jọkẹ Amọri Awọn oloye Olubadan ilẹ Ibadan ti gomina Ajimọbi fun lade ti paṣẹ pe ki…

Gbogbo ọmọ Edo lo fọwọ si i pe ki Ọṣinbajo di aarẹ ni 2023- Igbakeji Gomina Edo

Adefunkẹ Adebiyi Igbakeji gomina ipinlẹ Edo, Philip Shaibu, ti fi atilẹyin rẹ ati ti gbogbo ọmọ…

Eeyan mẹta ku, ọpọ fara pa, nibi ija ọlọpaa ati akẹkọọ Kwara Poli n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ṣe ni ọrọ di bo o lọ o yago lọna, lowurọ kutu ọjọ…

N’Ileṣa, owo ‘ọmọ onilẹ’ di wahala laarin awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun, eeyan marun-un lo ku

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ṣe lawọn eeyan ilu Ileṣa, nipinlẹ Ọṣun, n gbe tifura-tifura bayii latari wahala…

Ipo Olubadan: Awọn ọba Ajimọbi pohun da, wọn lawọn yoo maa ba ẹjọ to wa ni kootu lọ

Jọkẹ Amọri Pẹlu bi nnkan ṣe ri yii, yoo pẹ diẹ ki ilu Ibadan too le…

Ọlọpaa bẹrẹ iwadii lori Ẹbunoluwa ti wọn pa sinu ile awọn obi rẹ l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti bẹrẹ iwadii lori iku ọmọbinrin ẹni ogun ọdun…

Nitori iṣẹlẹ idigunjale to n waye lemọlemọ, Ọọni paṣẹ iṣede niluu Ileefẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọọni Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ogunwusi, ti paṣẹ iṣede laarin ilu naa lati aago…

L’Agbado, Diran ba iyawo ẹ atijọ lo pọ lotẹẹli, lo ba gbabẹ ku

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bi wọn ba n ṣadua pe ka ma gba ibi ta a gba…