Ijọba ṣawari mọṣuari tawọn agbenipa n gbe oku si n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọbọ, Tọsidee, ọjọ kẹẹẹdogun, oṣu Keji yii, ni ijọba ipinlẹ Kwara, ti mọsuari…

Nitori owo tikẹẹti, agbero fun onikẹkẹ lọrun pa

Monisọla Saka Ọkan lara awọn agbero to n jawe fawọn onimọto ati ọlọkada nipinlẹ Delta, Task…

Ọga ọlọpaa kowo jẹ, wọn ti yọ ọ bii jiga nipo

Monisọla Saka Kọmiṣanna ọlọpaa ipinlẹ Delta, CP Abaniwọnda Olufẹmi, ti paṣẹ pe ki wọn gbọn SP…

Nitori iṣẹlẹ ijinigbe ojoojumọ, ibẹru gb’ọkan awọn eeyan Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Inu ibẹru nla lawọn eeyan Akoko ati Ọwọ, eyi to wa lẹkun Ariwa…

Ijọba pin nnkan ija loriṣiiriṣii fawọn ẹṣọ alaabo l’Ekiti

 Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ni ilakaka ijọba ipinlẹ Ekiti lati fi opin si eto ijinigbe ati iṣeku…

Gomina Ayedatiwa gba awọn ọba Yoruba nimọran

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina ipinlẹ Ondo, Ọnarebu Lucky Orimisan Ayedatiwa, ti gba awọn ọba ilẹ Yoruba…

Tinubu, awọn gomina fọwọ si idasilẹ ọlọpaa ipinlẹ

Jọkẹ Amọri Nibi ipade pajawiri kan ti ijọba apapọ ati awọn gomina kaakiri ipinlẹ mẹrẹẹrindinlogoji to…

Nibi ti nnkan le de bayii, a ko mọ bi a ṣe maa ba araalu sọrọ mọ o- Emir Oke-Ọya

Adewale Adeoye Agbarijọpọ ẹgbẹ awọn Emir Oke-Ọya, labe ẹgbẹ kan ti wọn n pe ni ‘Northern Traditional Council’ (NTC), eyi ti Emir ipinlẹ Kaduna, Alhaji Muhammad…

Iyaale ile yii ge ‘kinni’ ọkọ  rẹ  bọ silẹ lọganjọ oru, o lo n yan ale

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Chota, lorileede Peru, ti lawọn maa too bẹrẹ iwadii lori ẹsun ti wọn fi kan…

Aṣiri tu! Ọwọ tẹ ọmọ ogun oju ofurufu ilẹ wa to n ta nnkan ija oloro fawọn agbebọn

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa orileede wa ti fọwọ ofin mu Ọgbẹni Ahmed Mohammed, to ti figba kan jẹ ọmọ oju ogun…

Wọn ti mu awọn to n rọ ibọn atawọn ohun ija oloro fawọn afẹmiṣofo

Adewale Adeoye Ikọ  awọn ọmọ ogun orileede yii kan ti wọn n pe ni ‘Operation Safe Haven’ to wa nijọba ibilẹ Magnu, nipinlẹ Plateau, ti…