Wọn ti gbe Sunday Igboho de kootu, awọn ọba Yoruba ni Benin ṣatilẹyin fun un

Jọke Amọri Ni ba a ṣe n sọrọ yii, ajijagbara ọmọ Yoruba nni, Sunday Adeyẹmọ ti…

Wọn ti gbe Sunday Igboho de kootu, awọn ọba Yoruba ni Benin ṣatilẹyin fun un

Jọke Amọri Ni ba a ṣe n sọrọ yii, ajijagbara ọmọ Yoruba nni, Sunday Adeyẹmọ ti…

Buratai ti kọwe sijọba Olominira Benin, o ni ki wọn yọnda Sunday Igboho fawọn

Faith Adebọla Ọga ologun ilẹ wa tẹlẹ to tun jẹ aṣoju Naijiria ni orileede Olominira Benin,…

Ọga agbẹjọro kan lati orileede France ni yoo ṣiwaju awọn lọọya ti yoo duro fun Sunday Igboho ni kootu Benin

Jọke Amọri  Iroyin to n tẹ ALAROYE lọwọ bayii lori ọrọ ajijagbara ọmọ Yoruba nni, Oloye…

Eeyan mẹrin ku ninu mọlẹbi kan, meji dero ileewosan, eefin jẹnẹretọ lo pa wọn ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin O kere tan, eeyan mẹrin ti ku ninu mọlẹbi kan, ti meji si…

Awọn ọlọpaa ti mu dẹrẹba ti wọn lo fẹẹ ta ero ọkọ rẹ fawọn ajinigbe l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ọlọpaa ipinlẹ Ekiti ti tẹ awakọ bọọsi kan ti wọn ṣafihan rẹ ninu…

Iṣoro Naijiria kọja eyi ti Buhari le yanju, ki ẹnikẹni ma ro pe ayipada yoo wa ṣaaju 2023 – Biṣọọbu Adeoye

Alukooro igbimọ awọn Biṣọọbu lagbaaye (World Bishops Council) nilẹ Afrika, Biṣọọbu Ṣeun Adeoye, ti sọ pe iṣoro…

Sunday Igboho yoo fara han nile-ẹjọ lorileede Benin

Faith Adebọla Bi gbogbo nnkan ba lọ bi wọn ti ṣeto rẹ, aarọ Ọjọbọ, Tọsidee yii…

Ẹgbẹ ọdọ Yoruba rọ awọn agbaagba lati gba Sunday Igboho silẹ lọwọ ijọba Benin ati Naijiria

Ọlawale Ajao, Ibadan Ẹgbẹ awọn ọdọ Yoruba, iyẹn Yoruba Youth Socio-Cultural Association (YYSA), ti sọ pe…

Ọkada ni Taofeek ji gbe tọwọ NSCDC fi tẹ ẹ lọjọ ọdun Ileya n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ajọ ẹsọ alaabo ṣifu difẹnsi, ẹka ti ipinlẹ Kwara, ti mu adigunjale kan,…

Wọn ti gbe Sunday Igboho lọ sile-ẹjọ ni Cotonou

Faith Adebọla Iroyin to tẹ ALAROYE lọwọ ni pe wọn ti gbe gbaju-gbaja ajafẹtọọ ọmọniyan to…