Adehun ti wa nilẹ pe Tinubu ni Buhari maa gbejọba fun- Hanga

Faith Adebọla “Aṣiri to foju han ni, ki i ṣe ọrọ abumọ rara, adehun wa laarin…

Awọn agbebọn to ji onisowo gbe n’llọrin n beere fun miliọnu mẹwaa naira

Ibrahim Alagunmu Ilọrin, Ọjọruu, Wẹsidee, ọṣẹ to kọja lawọn agbebọn to dihamọra pẹlu ibọn ji gbajugbaja…

Mi o fẹ Senabu mọ, igo lo maa n pa mọlẹ ta a ba n ja, bẹẹ lo maa n gbe mi ṣepe-Suraaju

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọgbẹni Surajudeen Sanyaolu lọkọ Senabu Sanyaolu, ọdun meji naa ni wọn ṣi fi…

Babalawo to ni Iyabọ Ojo maa ku lori ọrọ Baba Ijẹṣa ti ku o

Faith Adebọla, Eko Bo ba jẹ pe wọn ṣe oogun madarikan fun gbajugbaja oṣere ilẹ wa,…

Loootọ lawọn eeyan wa kọju ija sawọn onifayawọ n’Ibarapa-Ileeṣẹ Aṣọbode

  Ọlawale Ajao, Ibadan O kere tan, eeyan mẹta lo padanu ẹmi rẹ lasiko ifija pẹẹta…

Wọn pa Fulani darandaran sinu oko, wọn tun ge ẹya ara rẹ lọ ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn afurasi afini soogun owo ti ṣeku pa Fulani darandaran ẹni ogun ọdun,…

O ma ṣe o, ijamba ọkọ gbẹmi eeyan mẹrinla n’Ipetu-Ijeṣa

Ọmọ kekeke mẹfa ati agba mẹjọ ni wọn ku ninu ijamba ọkọ to ṣẹlẹ lalẹ ọjọ…

Ipo ti mo ba mọlẹbi ọmọbinrin ti wọn pa s’Ọjọta lasiko iwọde ‘Yoruba Nation’ ṣe mi laaanu lo jẹ ki n fun wọn lowo-Mr Macaroni

Faith Adebọla Gbajugbaja adẹrin-in poṣonu ilẹ wa nni, Ọgbẹni Debọ Adedayọ, tawọn eeyan mọ si Mista…

‘’Iṣoro ipinlẹ Ọyọ kọja ohun ti Makinde le fọgbọn ori yanju’’

Ọlawale Ajao, Ibadan Pẹlu bi ọrọ aabo ṣe dẹnu kọlẹ nipinlẹ Ọyọ lẹnu lọọlọọ yii, awọn…

Eeyan mẹwaa ku, ọpọ fara pa, nibi ijamba ọkọ ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Kwara O kere tan, eeyan mẹwaa ni wọn ti dagbere faye nibi ijamba ọkọ…

Wọn ti dajọ iku fun Morẹnikeji to fun iyawo ọga ẹ lọrun pa l’Ọyọọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori bo ṣe tan iyaale ile kan, Rachael Oyewumi Ayanwale, jade kuro nibi…