Eeyan mẹta ku ninu mọlẹbi kan, majele ni wọn jẹ mọ amala n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu Ilọrin, Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọṣẹ yii, ni eeyan mẹta ninu mọlẹbi kan tun ku lojiji…

Awọn agbebọn ji gbajumọ onisowo kan gbe n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu Ilọrin, Ọjọruu, Wẹsidee, ọṣẹ yii, lawọn agbebọn to dihamọra pẹlu ibọn ji gbajugbaja oniṣowo…

Ọbasanjọ gba Buhari nimọran: Ọwọ lile kọ o, lọọ pepade alaafia pẹlu awọn ti wọn fẹẹ ya kuro ni Naijiria  

 Faith Adebọla Aarẹ ilẹ wa tẹlẹ ri, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ, ti ṣekilọ pe afaimọ ki ọrọ…

Awọn janduku agbebọn yinbọn pa ọga ṣọja l’Abuja, wọn tun ji aburo ẹ gbe

Faith Adebọla Ko jọ pe awọn janduku agbebọn to n fojoojumọ ṣoro bii agbọn nilẹ wa…

Ijọba kede ọjọ Iṣẹgun ati Ọjọruu gẹgẹ bii ọlude ọdun Ileya

Faith Adebọla Ijọba apapọ ti kede ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ogunjọ, ati Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kọkanlelogun, oṣu…

Arọọda ojo ṣọsẹ l’Ekiti, o ba ọpọlọpọ dukia jẹ

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ko din ni ogun eeyan lara awọn olugbe ilu Ado-Ekiti, to ti di…

 Awọn adigunjale fọ banki n’Ilara-Mọkin, wọn yinbọn pa eeyan mẹta

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Eeyan mẹta ni wọn pade iku ojiji lasiko tawọn adigunjale kan fọ banki…

Korona pada de! O paayan meji l’Ogun, awọn mẹẹẹdogun mi-in tun fara ko o

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Laarin ọsẹ mẹta si asiko yii, eeyan meji ni arun aṣekupani Korona to…

Awọn ajinigbe ji arinrin-ajo mẹfa gbe ni aala ipinlẹ Ondo ati Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Awọn afunrasi ajinigbe kan ti wọn ko ti i mọ ti ji awọn…

O ṣẹlẹ, ẹgbẹ APC da awọn ọmọ ẹyin Lai Muhammed mọkanla duro ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ẹgbẹ oṣelu APC, ẹka ti ipinlẹ Kwara, ti da ọmọ ẹgbẹ mọkanla to…

Awọn ẹlẹsin abalaye fẹhonu han nitori Eṣuleke tijọba fẹsun ipaniyan kan l’Oṣogbo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Agbarijọpọ ẹgbẹ awọn ẹlẹsin ibilẹ kaakiri ipinlẹ Ọṣun, Traditional Religion Worshippers Association State…