Ile-ẹjọ fiwe ti yoo pọn ayẹwo ẹjẹ ọmọ Mohbad ni dandan ranṣẹ si Wumi

Faith Adebọla Ni bayii, dandan lowo-ori, ọran-an-yan laṣọ ibora, lọrọ ayẹwo ẹjọ Liam, da fun Wumi,…

O tan! Portable ko Olori Alaafin tẹlẹ, Queen Dami, sita bii ọmọ ọjọ mẹjọ

Monisọla Saka Gbajumọ olorin taka-sufee tẹnu ki i sin lara rẹ, Habeeb Okikiọla Ọmọ Ọlalọmi Badmus,…

Adeleke buwọ lu ami idanimọ tuntun fun ipinlẹ Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina Ademọla Adeleke ti buwọ lu ofin to ṣagbekalẹ ami idanimọ tuntun fun…

Ẹ la awọn araalu lọyẹ ki ẹ too maa mu wọn fun ẹsun ṣiṣe Naira baṣubaṣu-Oluwoo  

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Pẹlu bi ajọ to n gbogun ti ṣiṣe owo araalu baṣubaṣu, EFCC, ṣe…

Awọn tọwọ tẹ lori ọrọ ominira ilẹ Yoruba ti dero ọgba wọn 

Ọlawale Ajao, Ibadan O kere tan, ọjọ marunlelọgọrun-un (105) lawọn afurasi ọdaran tọwọ tẹ lori iditẹgbajọba…

Ọwọ tẹ alaga ẹgbẹ awakọ pẹlu awọn ohun eelo idibo abẹle l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Nibi to ti n ṣeto ayederu iforukọ silẹ fun awọn ọmọ ẹgbẹ All…

Eyi ni bi awọn kọsitọọmu ṣe gba ẹgbaagbeje ọmọ Naijiria lọwọ iku ojiji

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọkẹ aimọye alaisan lorileede yii ni iba ra oogun fun iwosan ara wọn…

Awọn eleyii yoo pẹ lẹwọn o, agbẹ kan ni wọn pa sinu oko rẹ ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ile-ẹjọ Majisireeti kan to filu Ilọrin nipinlẹ Kwara, ṣebujokoo ti paṣẹ pe ki…

O ma ṣe o, lasiko ti wọn n ja epo ni mọto yii gbina, o si jona gburugburu 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Iran buruku niran to ṣẹlẹ lọṣan-an Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kẹtadinlogun, oṣu Kẹrin, ọdun…

Ẹ woju adigunjale mẹta ti wọn n han araalu leemọ l’Ọta

Faith Adebọla Pampẹ ofin awọn agbofinro ipinlẹ Ogun ti mu awọn adigunjale mẹta kan, Abayọmi Michael…

Iya Mohbad pariwo: Ẹ gba mi o, awọn kan n lepa emi mi, wọn fẹẹ pa mi o

Monisọla Saka Iya to bi gbajumọ ọkunrin olorin taka-sufee ilẹ wa to ku lọdun to kọja…