Eyi ni fidio ibura tawọn eeyan n sọ pe gomina Ekiti tẹlẹ, Ayọdele Fayoṣe, fi ṣe…
Category: Ìròyìn
Ibo abẹle Ondo: Kekemeke loun ko ni igbẹkẹle ninu ẹ, Abraham naa binu kuro
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkan ninu awọn to n dije sipo gomina ninu eto idibo to n…
Ọwọ ijọba lo wa ti iwa ifipabanilopọ yoo ba dẹkun lorileede yii – Ẹlẹbuibọn
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Araba awo ti ilẹ Oṣogbo, Oloye Ifayẹni Ẹlẹbuibọn ti sọ pe ti iwa…
Ẹ woju wọn o: Awọn ọmọde Fulani adigunjale lọna Ibadan
Awọn Fulani ọmọde kan ti wọn ko ti i pe ọmo ogun ọdun ti wa lọna…
LONI-IN, AKEREDOLU YOO KOJU AWỌN ALATAKO Ẹ NINU APC L’ONDO
Boya Arakunrin Rotimi Akeredolu yoo tun ṣe gomina ipinlẹ Ondo lẹẹkan si i tabi ala ti…
FA Cup: Arsenal ati Chelsea yoo koju ara wọn fun aṣekagba
Oluyinka Soyemi Ẹgbẹ agbabọọlu Arsenal ati Chelsea yoo pade nibi aṣekagba idije FA Cup lọjọ kin-in-ni,…
Tẹgbọn-taburo dero ẹwọn, igbo ni wọn ka mọ wọn lọwọ n’Ileefẹ
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ṣebi ọmọ-iya meji ki i ṣe owo aipe lawọn agbalagba maa n wi,…
Ẹ WOJU Ẹ: ẸNI TO PA TOLULỌPẸ AFẸRONPILEENI-JAGUN REE O
Ileeṣẹ ologun ofurufu ilẹ wa ti kede, lọṣan-an yii, oruko ẹni to pa Tolulọpẹ Arotile, ọmọbinrin…
Ileeṣẹ agunbanirọ fiya jẹ mọkanla ninu wọn to n sa lẹnu iṣẹ
Ọlawale Ajao, Ibadan Yatọ si awọn meji to j’Ọlọrun nipe lasiko ti wọn n ṣiṣẹ sin…
Iru ki waa leleyii! Sherifat n mura idanwo Wayẹẹki lọwọ lo fi binu para ẹ n’Ikorodu
Faith Adebọla Orin wo la fẹẹ kọ si gbẹdu lọrọ da pẹlu bi ibanujẹ ati ọgbẹ…
O TAN! ARUN KORONA TI MU MINISITA BUHARI O
Ọkan ninu awọn minisita ti wọn n ba Aarẹ Muhamadu Buhari ṣiṣẹ ninu jjọba rẹ yii…