Awọn agbebọn ji aburo ọba alaye gbe ni Kwara, igba miliọnu ni wọn n beere

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Abamẹta Satide, opin ọsẹ to kọja yii, ni awọn awọn agbebọn ya…

Ẹgbẹ PDP ati APC sọko ọrọ sira wọn nitori bi Fayemi ṣe ti ileewe pa fun ọsẹ meji l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ẹgbẹ Alaburada (PDP) ati ẹgbẹ Onigbaalẹ (APC) ni wọn ti n sọrọ kobakungbe…

Awọn ọmọọṣẹ Igboho meji yoo tun foju bale-ẹjọ lọsẹ yii

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Amudat Babatunde ati Jamiu Oyetunji ti wọn jẹ ọmọ ẹyin Sunday Igboho yoo…

Adedoyin: Ọjọ Aje lawọn dokita yoo ṣayẹwo iru iku to pa Timothy-Ọlọkọde

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lati le mọ iru iku to pa Timothy Adegoke, akẹkọọ Fasiti Ifẹ to…

Makinde sanwo ti wọn yoo fi bẹrẹ idasilẹ ẹka LAUTECH niluu Iṣẹyin

Ọlawale Ajao, Ibadan Owo to to ẹẹdẹgbẹta miliọnu Naira ni Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde,…

 Muhammed dero ẹwọn l’Akurẹ, ọmọ ọga rẹ lo fibinu lu pa

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Adajọ Ile-ẹjọ giga to wa l’Akurẹ, Onidaajọ Adeyẹmi Fasami, ti ni ki ọkunrin…

Tori owo ti wọn bun un to fẹẹ fi ta awọn ọmọ orukan lọrẹ, ijọba Eko gboṣuba fun Davido

Faith Adebọla, Eko  Ijọba ipinlẹ Eko ti gboṣuba sadankata fun gbajugbaja akọrin taka-sufee ọmọ Yoruba nni,…

O ma ṣe o, Sẹnetọ Gbenga Aluko ku lojiji

Ọkan ninu awọn ọmọ ile-igbimọ aṣofin ilẹ wa tẹlẹ, Sẹnetọ Gbenga Aluko, la gbọ pe o…

Ileeṣẹ Glo fẹbun pataki ta awọn onibaara wọn lọrẹ

 Adefunkẹ Adebiyi Ileeṣẹ ẹrọ ibanisọrọ nni, Globacom, ti kede pe ko din ni onibaara mẹtalenigba (203)…

Baba agbalagba tọwọ tẹ nibi to ti n hu oku olokuu l’Ondo ti foju bale-ẹjọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Baba agbalagba kan, Lasisi Isiaka, lawọn ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti wọ lọ sile-ẹjọ…

Adajọ ti ni ki wọn ju akẹkọọ Fasiti Ilọrin to lu tiṣa rẹ sẹwọn

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Yoruba ni ẹlẹṣẹ kan ki i lọ lai jiya, Adajọ Muhammed Ibrahim, tile-ẹjọ…