Ti o ba jẹ pe aṣiri tu, diẹ lo ku kawọn tọkọ-taya ọran yii sọ idunnu…
O ma ṣe o, ‘Dudu Heritage’, ọkọ Bimbọ Ọshin, ku lojiji
Ajalu buruku ni iku iku Ọla Ibironkẹ ti gbogbo eeyan mọ si Dudu Heritage to jẹ…
Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun pa ara wọn l’Oṣogbo, mẹwaa lara wọn lọwọ ọlọpaa ti tẹ
Florence Babaṣọla Ọmọkunrin kan ti wọn pe orukọ rẹ ni Aniyikaye lawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ti…
Wọn ti mu ọlọpaa to yinbọn pa Mọnsurat n’Ijẹṣatẹdo
Faith Adebọla, Eko Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ti rawọ ẹbẹ sawọn mọlẹbi ọmọbinrin ẹni ọdun mejidinlogun…
Awọn ọba alaye ṣewọde l’Ekiti, nitori ijọba ibilẹ tuntun ti Fayemi gbe kuro lọdọ wọn
Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ko din ni kabiyesi meje lati ijọba ibilẹ Ikọle, nipinlẹ Ekiti, ti wọn…
Ẹ ṣaa jẹ ki Buhari da Naijiria pada si ipo to ba a nigba to de– Imaamu agba l’Abuja
Faith Adebọla Olori ẹsin Musulumi kan to n ṣaaju mọṣalaṣi Ẹsiteeti tawọn aṣofin apapọ n gbe,…
Lanre Gentry, ọkọ Mercy Aigbe tẹlẹ, ṣegbeyawo alarede
Faith Adebọla, Eko Igbeyawo alarede mi-in ni ọkọ gbajugbaja oṣere tiata ilẹ wa nni tẹlẹ, Mercy…
Ṣẹgun ki i ṣe ṣọja, lasiko to wọṣọ ologun lati gba afurasi silẹ lọdọ ọlọpaa ni wọn mu un ni Sango
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ṣẹgun Ogundeji lo duro bii ṣọja kekere yii, ṣugbọn ki i ṣe ṣọja,…
Idajọ ododo la fẹ lori awọn tọọgi to ba ileeṣẹ burẹdi wa jẹ n’Iwo – Taawun
Florence Babaṣọla Agbarijọ ẹgbẹ awọn Musulumi kan niluu Iwo, Jama’at Taawunil Muslimeen, ti sọ pe afi…
Kayeefi! Ọkunrin yii n ba iya rẹ laṣepọ titi to fi bimọ mẹta fun un ni Kwara
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ajọ ẹsọ alaabo ṣifu difẹnsi, ẹka ti ipinlẹ Kwara, ti mu ọkunrin ọmọ…
Ara Iyabo Oko onitiata ko ya gidigidi, o nilo iranlọwọ ọmọ Naijiria
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lasiko ti a n kọ iroyin yii lọwọ, inu aarẹ nla ni agba…