O Soju Mi Koro

Alagbara lanaa da: Oshiomhole to fẹẹ gbẹsan Nigba ti Ọlọrun ba fun ni lagbara, ko si ohun to dara bii ka mọ pe Ọlọrun lo fun ni lagbara naa, o si le gba a nigbakugba to ba fẹ. Ohun ti eyi fi dara ni pe bi a ba ti n …

Read More »

Wọn ṣi n wa awọn arinrinajo mẹjọ ti wọn ji gbe ni Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Titi di ba a ṣe n sọ yii lawọn agbofinro atawọn ẹṣọ alaabo lẹlẹka-jẹka ṣi n wa awọn arinrinajo kan ti wọn lawọn agbebọn ji gbe lagbegbe Akoko lọjọ Ẹti, Furaidee, ọsẹ to kọja. ALAROYE gbọ pe awọn arinrinajo ọhun ti wọn to bii mẹsan-an ni wọn n bọ lati ilu Abuja lasiko …

Read More »

Nwakali gba bọọlu fun kilọọbu lẹyin ọdun kan

Oluyinka Soyemi Lẹyin ọdun kan ati oṣu mẹta ti balogun ikọ agbabọọlu Golden Eaglets ilẹ Naijiria tẹlẹ, Kelechi Nwakali, ti gba bọọlu fun kilọọbu gbẹyin, o ti kopa ninu ifẹsẹwọnsẹ akọkọ fun Huesca, ilẹ Spain, bayii. Eyi waye l’Ọjọbọ, Tọsidee, to kọja, nibi ti kilọọbu naa ti jiya ami-ayo kan …

Read More »
//eephaush.com/4/4998019