Awọn ọmọ Yoruba ṣedaro Olupo tilu Ajaṣẹ-Ipo to waja

Stephen Ajagbe, Ilorin Awọn araalu ṣedaro Olupo tilu Ajaṣẹ-Ipo, Ọba Sikiru Atanda Ọladọtun Wọleọla (Ilufẹmiloye) to…

Awọn eleyii n fẹwọn ṣere, irin reluwee ni wọn lọọ ji ko n’Ijọra

Faith Adebọla Ibi tọkanjuwa ẹni ba so si leeyan ti n ka a loootọ, ṣugbọn ni…

Ọga kọsitọọmu ku sibi to ti lugọ de awọn onifayawọ ni Ṣaki

Olu-Theo Ọmọlohun, Oke Ogun     Titi dasiko yii lawọn eeyan ṣi n ṣawuyewuye nipa iku…

Ẹ wo Kabiru, ayederu ṣọja to n halẹ m’awọn araalu

Faith Adebọla, Eko     Beeyan ba ri ọkada ti Kabiru Mohammed yii n gun lọọọkan,…

Bijọba ko ba fopin si bi wọn ṣe n pa awọn eeyan wa, a ko ni i ta maaluu ati ohun jijẹ mọ-Tahir

Ẹgbẹ kan to ni i ṣe pẹlu awọn Fulani darandaran atawọn to n ta ohun jijẹ…

Ko sẹni to le gba ipo mi ninu ẹgbẹ APC l’Ọṣun, Arẹgbẹ fọwọ sọya

Florence Babaṣọla Gomina ipinlẹ Ọṣun tẹlẹ, Ọgbẹni Rauf Arẹgbẹṣọla ti fọwọ mejeeji sọya pe ko si…

Ikilọ lati dẹkun dida abẹ fobinrin bẹrẹ l’Ekiti lakọtun

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Latari bi aṣa didabẹ fun obinrin ko ṣe ti i di ohun igbagbe…

Lẹyin ọdun mẹjọ to ti paayan ni Mowe, Sheu gbadajọ iku l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Gẹgẹ bi akọsilẹ kootu ṣe wi, ọjọ kẹẹẹdogun oṣu kẹsan-an ọdun 2013 ni ọkunrin…

Nibi ti Ayuba atọrẹ ẹ ti n fibọn jale lọwọ l’Agboju lawọn ọlọpaa ti ko wọn

Faith Adebọla, Eko Ahamọ ọlọpaa ọtẹlẹmuyẹ to wa ni Panti, Yaba, nipinlẹ Eko, lawọn afurasi ọdaran…

Akeredolu yan akọwe fawọn ijọba ibilẹ mejidinlogun to wa nipinlẹ Ondo

Gomina Rotimi Akeredolu ti fọwọ si yiyan awọn akọwe fun ijọba ibilẹ mejidinlogun to wa nipinlẹ…

 Nitori obinrin, Naso gun ara ile rẹ pa loju oorun l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkunrin ọmọ ibo kan tawọn eeyan mọ si Naso ti n sọ tẹnu…