Ẹwọn n run nimu Ọmọlade, iya onirẹsi lo lu ni jibiti owo nla n’Ileefẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Apo irẹsi ọgọrun-un ni wọn ni Oyetoro Ọmọlade gba lọwọ Alhaja Eluwọle Sẹrifat…

Ijọba fẹẹ ka iye awọn eeyan to talaka ju lọ l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii ni eto kika iye eeyan ti oṣi ati…

Ọpẹ o, awọn ọlọpaa ti ri Sunday to n paayan l’Akinyẹle to sa lọ n’Ibadan mu

Ọlawale Ajao, Ibadan Alukoro ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Ọyọ, Olugbenga Fadeyi, ti fidi rẹ mulẹ pe ọwọ…

Ideye darapọ mọ Goztepe ilẹ Turkey

Oluyinka Soyemi Agbabọọlu ilẹ Naijiria, Brown Ideye, ti darapọ mọ ẹgbẹ agbabọọlu Goztepe ilẹ Turkey. Gẹgẹ…

Ọwọ ti ba ‘Stubborn’, ogbologboo ọmọ ẹgbẹ okunkun n’Ilaro

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta O pẹ tawọn ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti n wa Dare Ojugbele tawọn eeyan…

Awọn ọlọpaa ti mu un o: Emmanuel to n fi igbẹ jẹ burẹdi nIbadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Bi ko je awọn ọlọpaa ti wọn tete debẹ ni, afaimọ lawọn ara…

Iyawo Buhari ti de lati Dubai, o ni diẹ lo ku ki ẹronpileeni awọn ja bọ

Iyawo Aarẹ orilẹ-ede yii, Aisha Buhari, ti de lati ilẹ Dubai to lọ o. Ọsẹ bii…

Lẹyin ọsẹ meji tawọn meji ku, kọntena tun ja bọ lu eeyan meji ni Ijeṣha

Faith Adebọla Ko ti i pe oṣu kan ti awọn meji kan ku lojiji pẹlu bi…

Aye le o! Ọmọ ọdun mẹrindinlogun ji pata obinrin mẹrinla l’Ayetoro

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Adeniyi Muhammed lorukọ ọmọdekunrin ti ẹ n wo yii, ọmọ ọdun  mẹindinlogun ni. Niṣe…

Korona tun pa elomi-in l’Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ijọba ipinlẹ Ekiti ti kede pe arun Koronafairọọsi ti pa ẹni kan nipinlẹ naa…

O ṣẹlẹ, awọn kan ti lọọ ta ilẹ ooṣa n’Ibadan o

Ọlawale Ajao, Ibadan Iwure ati etutu lawọn ẹlẹsin abilẹ n’Ibadan n fi gbogbo igba ṣe bayii…