Awọn agbebọn pa ọlọpaa kan, wọn ji oyinbo gbe lọ ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn afurasi agbebọn kan  ti ya bo ọgba ileesẹ CGC Construction Company, l’Opopona…

Adajọ ti ran Aafaa Muastapha to fipa ba ọmọ ọdun mẹjọ lo pọ l’Ekoo lẹwọn gbere

Onidaajọ H. O. Oshodi ti ile-ẹjọ giga ipinlẹ Eko to fikalẹ siluu Ikẹja, ti sọ Aafaa…

Ibi ti Tinubu ti n gba itọju lọwọ lo wa lorileede France – Adamu Waziri

Faith Adebọla Ni iyatọ patapata si ọrọ tawọn amugbalẹgbẹẹ Aṣiwaju Bọla Tinubu sọ nipa irinajo rẹ…

Awọn afẹmiṣofo dena de Buhari ni Katsina, wọn ṣe ẹṣọ alaabo meji leṣe

Faith Adebọla Wahala awọn agbebọn afẹmiṣofo ati eto aabo to dẹnu kọlẹ lorileede wa tun gba…

Awọn afẹmiṣofo dena de Buhari ni Katsina, wọn ṣe ẹṣọ alaabo meji leṣe

Faith Adebọla Wahala awọn agbebọn afẹmiṣofo ati eto aabo to dẹnu kọlẹ lorileede wa tun gba…

Eeyan mẹjọ padanu ẹmi wọn nibi ija awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun

Monisọla Saka Ko din ni eniyan mẹjọ ti wọn ti dẹni ana nibi ikọlu awọn ọmọ…

Kayeefi kan ree o! Ọmọ ọdun meje to digunjale n’Ibadan ni: Ile mẹrin ni mo ti fọ laarin ọjọ meji

Ọlawale Ajao, Ibadan Ko si bi eeyan yoo ṣe gburoo ọmọ naa ti ọjọ iwaju ẹ…

Oludije APC, Oyebamiji, jawe olubori ni wọọdu rẹ

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ninu ibo ọọdunrun ti wọn di ni wọọdu oludije funpo gomina labẹ ẹgbẹ…

Ijọba ipinlẹ Eko gbẹsẹ le ilẹ ile alaja mọkanlelogun to wo n’Ikoyi

Monisọla Saka L’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, nijọba ipinlẹ Eko sọ pe awọn ti gba ilẹ ti…

Wọn sọ Nuhu sẹwọn tori iwa jibiti, wọn tun gbẹsẹ le dukia ẹ l’Ekoo

Faith Adebọla Ẹwọn oṣu mẹfa ni ọmọkunrin ti wọn porukọ ẹ ni Nuhu Zakari yii, yoo…

Ṣeun to gun ale rẹ lọbẹ l’Ondo ni ṣe loun fi daabo bo ara oun

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọmọbinrin ẹni ọdun mọkandinlogoji kan, Ṣeun Ṣọla ti ṣalaye idi to fi gun…