Timothy Adegoke: Ile-ẹjọ sọ pe ko tọna lati fun Adedoyin atawọn oṣiṣẹ rẹ ni beeli

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Titi di igba ti a n ko iroyin yii jọ, atotonu ti bẹrẹ…

Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ni ẹgbẹ PDP yoo yan oludije funpo gomina wọn l’Ọṣun 

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Lọwọlọwọ bayii, awọn aṣoju lati wọọdu idibo ojilelọọọdunrun o din mẹjọ (332) to…

Wọn ti ri oku ọmọbinrin ti dẹrẹba BRT gbe sa lọ ti wọn n wa

Jọkẹ Amọri Epe nla nla ni awọn eeyan ti wọn gbọ pe ọmọbinrin to n ṣiṣẹ…

Abba Kyari loun ko jẹbi ẹsun siṣe agbodegba oogun oloro

Jọkẹ Amọri Ẹsun mẹjọ ọtọọtọ ni ile-ẹjọ kan to jokoo niluu Abuja, niwaju Onidaajọ Emeka Nwite…

Igbẹjọ Timothy: Adajọ kọ lati fun Adedoyin atawọn ọmọọṣẹ rẹ ni beeli

Ile-ẹjọ to n gbọ ẹsun ti wọn fi kan Oloye Rahman Adedoyin to ni Hilton Hotel…

Iyawo Adeoti ti sọrọ: Oṣu marun-un ni ọmọ Mercy Aigbe wa toun at’ọkọ mi ti n bara wọn lo pọ

Ọrẹoluwa Adedeji Iyawo akọkọ ti ọkunrin makẹta ti ọkan ninu awọn oṣere ilẹ wa, Mercy Aigbe…

Lẹyin ti mo ba lo ọdun mẹjọ pe, oloṣelu to ba gbọn ṣaṣa ni ma a gbejọba fun – Tinubu

Gbenga Amos  Eekan oloṣelu, to tun jẹ gomina ipinlẹ Eko nigba kan, Aṣiwaju Bọla Ahmed Tinubu,…

Adeyẹmi ti jẹwọ o: Mo ji ewurẹ ti mo fi ṣekomọ ọmọ mi n’Ipokia

Gbenga Amos Ahamọ awọn ọtẹlẹmuyẹ ẹka ileeṣẹ ọlọpaa Idiroko lọkunrin ti wọn n pe ni James…

Fiimu ni Princess sọ pe a fẹẹ fi ọrọ ọmọ ti wọn ni mo fipa ba lo pọ ṣe, gbogbo ohun to ni ki n ṣe ni mo ṣe nibẹ

Faith Adebọla, Eko Ẹjọ ifipa ba ni lo pọ, iṣekuṣe ati hihuwa aidaa pẹlu ọmọbinrin ti…

Gbogbo ọmọ Ekiti lo wa lẹyin Tinubu lati ri i pe o wọle idibo ọdun 2023- Ewi Ado-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Gomina ipinlẹ Eko tẹlẹ, Asiwaju Bọla Tinubu, ti ṣalaye pe idi pataki toun…

Ẹ fi mi silẹ, ẹ jẹ ki n gbadun igbeyawo mi, bi mo ṣe jẹ iyawo keji lọọdẹ ọkọ mi ki i ṣe ohun toju ko ri ri-Mercy Aigbe

Ọrẹoluwa Adedeji Ọkan ninu awọn oṣere ilẹ wa to ṣẹṣẹ ṣegbeyawo laipẹ yii, Mercy Aigbe, ko…