Ẹwọn n run nimu Daniel, ọmọọlọmọ lo fipa ba laṣepọ niluu Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin       Afaimọ ki ọkunrin ẹni ọdun mẹrinlelogun kan, Daniel Lawrence, maa…

Wọn lu ọmọ ‘Yahoo’ pa ni Sagamu, wọn lo fẹẹ ji iya oniyaa to n gbalẹ ni titi gbe

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta   Ni fẹẹrẹ Ọjọbọ, ọjọ kẹẹẹdọgbọn, oṣu keji yii, ọmọkunrin kan ti wọn…

Ijamba ina fọpọ dukia ṣofo l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọpọ dukia lo ṣofo ninu ijamba ina kan to waye lagbegbe ileewe girama…

 N ko kabaamọ rara pe mo kuro lọfiisi gẹgẹ bii igbakeji gomina Ondo-Agboọla

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Mi o kabaamọ rara pe mo kuro lọfiisi gẹgẹ bii igbakeji gomina ipinlẹ…

Eeyan kan ku nibi ija ilẹ n’Ileefẹ

Florence Babasọla Ọkunrin kan la gbọ pe o ti dagbere faye lasiko ija ilẹ to bẹ…

Laipẹ yii ni wahala ẹgbẹ oṣelu PDP yoo rokun igbagbe – Oyinlọla

Florence Babaṣọla Alaga igbimọ to n pẹtu saawọ aarin awọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu PDP niha Iwọ-Oorun…

Ọlọpaa ti mu meji lara awọn janduku to fajọngbọn l’Ebute-Mẹta

Faith Adebọla, Eko       Latari bawọn janduku kan ṣe da wahala silẹ l’Opopona Herbert Macauly, lagbegbe Ebute-Mẹta,…

Ileeṣẹ ọlọpaa bẹrẹ iwadii lori oku Kabiru ti wọn ba lorita Ọkinni, nipinlẹ Ọṣun

Florence Babaṣọla       Alukoro ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun, SP Yẹmisi Ọpalọla, ti sọ pe…

Wọn ṣebura fun Akeredolu sipo gomina Ondo lẹẹkeji

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ   Ẹsẹ o gbero ni gbọngan asa igbalode Doomu to wa loju ọna…

Wahala Arẹgbẹṣọla ati Oyetọla: Ẹgbẹ igbimọ agba APC l’Ọṣun sọ pe ilẹkun awọn ṣi silẹ f’Omiṣore

Florence Babaṣọla Pẹlu bi wahala aarin Ọgbẹni Rauf Arẹgbẹṣọla ati Gomina Gboyega Oyetọla ṣe n fojoojumọ…

Ile-ẹjọ faini DPO to lu telọ rẹ lalubami n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan       Ọga ọlọpaa, iyẹn DPO tẹlẹ, lagọọ ọlọpaa Iyaganku, CSP Alex…