Ẹ sọ fun pasitọ ko sanwo to fi ra ilẹ to fi kọ ṣọọṣi ati apẹ-irin to fi pọn mọinmọin lọjọ ajọdun to ya lọwọ mi-Lanledi

Ọlawale Ajao, Ibadan Iya ẹni ọdun mẹtadinlaaadọrin (67) kan, Alhaja Modupẹ Animaṣahun, ti pe pasitọ ṣọọṣi…

Fidio: Mo ṣẹṣẹ fẹẹ bẹrẹ pẹlu awọn Fulani ni bayii- Sunday Igboho

Ọkan pataki ninu awọn ajijagbara ilẹ Yoruba, Oloye Sunday Igboho, ti gbogbo eeyan mọ si Igboho…

Ijamba ina jo ile awọn akẹkọọ pẹlu ẹru nileewe girama Ọffa

Stephen Ajagbe, Ilorin   Awọn ẹru ti ko niye nijamba ina kan to ṣẹlẹ nirọlẹ ọjọ…

Ọwọ ti tẹ Emmanuel atawọn ọrẹ rẹ ti wọn n fibọn gba ọkada n’Ileefẹ

Florence Babaṣọla Iroyin ayọ lo jẹ fun awọn ọlọkada ilu Ileefẹ, nigba ti wọn gbọ pe…

EndSars: Igbimọ oluwadii sọ pe ki awọn oṣiṣẹ ajọ Sifu Difẹnsi meji fara han lori iku Idris Ajibọla

Alaga igbimọ tijọba ipinlẹ Ọṣun gbe kalẹ lati ṣewadii iwa awọn ọlọpaa SARS, Adajọ-fẹyinti Akin Ọladimeji,…

Awọn aṣofin Ọ̀yọ́ gba ijọba nimoran lati gbe ọja Ṣáṣá lọ sibomi-in

Ọlawale Ajao, Ibadan   Ileegbimọ aṣofin ipinlẹ Ọyọ ti dabaa pe kí ìjọba ipinlẹ naa gbe…

Fidio: Awọn ṣọja lo ṣatilẹyin dáwọn Hausa ti wọn fi jo ile ati ṣọobu awọn Yoruba

Baálẹ̀ Ṣàṣà, Oloye Akinlade Àjàní ti sọ pe ko si ootọ́ ninu ọrọ ti Seriki Ṣàṣà…

Lori ọrọ ileewe tawọn olowo-ori ti pa, ijọba Ekiti tọrọ aforiji

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ijọba ipinlẹ Ekiti ti tọrọ aforiji lori iṣẹlẹ to waye l’Ọjọru, Wẹsidee, ọsẹ…

Ajoji tabi ẹni ti yoo maa ṣe ọmọọdọ fawọn kan ko ni i jẹ gomina Ekiti lọdun 2022 – Ojudu

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Oludamoran pataki fun Aarẹ Muhammadu Buhari lori ọrọ oṣelu, Sẹnetọ Babafẹmi Ojudu, ti…

Idi ti mo fi n pariwo pe ka ṣe suuru pẹlu ọrọ awọn Fulani – Oluwoo

Florence Babaṣọla Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti kilọ fun gbogbo awọn igi…

Dapọ Abiọdun gbe abajade ikọlu awọn Fulani ati agbẹ ipinlẹ Ogun lọ sọdọ Buhari

Gomina ipinlẹ Ogun, Ọmọọba Dapọ Abiọdun, ree pẹlu Aarẹ Muhammadu Buhari, lasiko ti Gomina gbe akojọpọ…