Saheed to fipa ba ọmọọdun mẹrinla laṣepọ foju bale-ẹjọ

Faith Adebọla, Eko Ahamọ ẹwọn Kirikiri, l’Ekoo, nile-ẹjọ Majisreeti to wa n’Ikẹja paṣẹ pe ki wọn…

Agbẹjọro to fọbẹ gbigbona jo ọmọ aburo ẹ lara tori ẹẹdẹgbẹta Naira ti dero ẹwọn

Faith Adebọla  Tori ko sẹni ti ida ofin ko le ge, Abilekọ Aina Ọdetayọ, ẹni ọdun…

Wọn lọmọbinrin yii lọọ ṣere fawọn ọlọjọọbi leti okun Eko, lo ba ku somi

Faith Adebọla, Eko  Ọdọmọbinrin ẹni ọdun mọkanlelogun kan, Michelle Abẹṣin, oṣere to n ṣiṣẹ DJ lode…

 Ẹ woju Taiwo, ayederu ṣọja tọwọ tẹ l’Okitipupa

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ayederu sọja kan, Lawal Taiwo, lọwọ awọn agbofinro tẹ niluu Okitipupa lọsẹ to…

Ẹwọn n run nimu  Benjamin o, ọmọ ọdun mẹtadinlogun lo fipa ba laṣepọ n’lọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọkunrin kan, Kposu Benjamin, ti dero ọgba ẹwọn bayii, ile-ẹjọ lo paṣẹ bẹẹ…

Tanka epo gbina n’Ibadan, ọkọ mẹta jona guruguru

Ọlawale Ajao, Ibadan Tanka epo nla kan pẹlu ọkọ ayọkẹlẹ meji lo ṣegbe sinu ijanba ina…

Awọn TOP fẹsun kan Oyetọla, wọn lo ran tọọgi lati da ipade awọn ru

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ere asapajude lawọn eeyan agbegbe Gbodofọn ati Fakunle, niluu Oṣogbo, sa lọsan-an Ọjọbọ,…

Ọlọpaa ko awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun kaakiri ipinlẹ Ogun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Nitori bawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun Ẹyẹ ati Aye ṣe di ẹrujẹẹjẹ sawọn eeyan lọrun…

Adedoyin: Wọn ko yọ ohunkohun lara akẹkọọ Fasiti Ifẹ ti a hu oku rẹ jade-Ọlọpaa

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Alukooro ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Ọṣun, SP Yẹmisi Ọpalọla, ti sọ pe ko si…

Obinrin to loyun oṣu mẹjọ sinu ni Wolii Festus loun fẹẹ ṣe itusilẹ fun, lo ba fipa ba lo pọ l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ariwo, ‘emi naa kọ, mi o mọ-ọn-mọ ṣe e, eṣu lo ti mi’…

Awọn aṣofin Ogun ni k’ọlọpaa mu Goriọla Hassan nibikibi ti wọn ba ti ri i

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ohun ti ileegbimọ aṣofin ipinlẹ Ogun n ba Goriọla Hassan fa nipa ọba…