A ṣi n ṣakojọpọ iwa itapa-sofin tawọn to n beere Orilẹ-ede Yoruba hu l’Abẹokuta- Oyeyẹmi

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Alukoro ọlọpaa nipinlẹ Ogun, DSP Abimbọla Oyeyẹmi, ti sọ pe ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ…

Iru ki waa leleyii, ọkada meji fori sọ tirela l’Abẹokuta, lo ba tẹ wọn pa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ni nnkan bii aago mẹjọ kọja iṣẹju mẹẹẹdọgbọn alẹ ọjọ Ẹti, ọgbọnjọ, oṣu…

Olori Ijo Ansarudeen, Shehu Ahmad, yoo ba gbogbo Musulumi aye sọrọ loni-in o

Nitori bi nnkan ṣe n lọ ni Naijiria wa loni-in yii, ati nitori asiko ti a…

Nibi ti Kelechukwu atọrẹ ẹ ti fẹẹ lu mọtọ ti wọn ji gbe ta ni gbanjo lọwọ ti tẹ wọn l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Ọrẹ lawọn mejeeji pe ara wọn, Kelechukwu Nnonyelu ati Godspower Okongi, ṣugbọn ọrẹ…

Tirela lọọ ya ba awọn obinrin oniṣowo mẹwaa ninu ọja, lo ba tẹ wọn pa

A-gbọ-fọwọ-gbari-mu ni iku ojiji to ṣe kongẹ awọn obinrin oniṣowo mẹwaa ti tirela akoyọyọ pa nifọnna…

Baba Ijẹṣa ki i ṣe ọmọ ẹgbẹ wa o- Mr LATIN

Nigba ti ọrọ Baba Ijẹṣa yii ko yee tan kiri, to ti di ohun ti wọn…

Ọwọ ẹsọ Amọtẹkun tẹ awọn Fulani bii aadọta to ya wọ Okitipupa loru

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Ọgọọrọ awọn Fulani darandaran kan ti wọn deedee ya bo Okitipupa, nijọba ibilẹ…

Ọwọ tẹ awọn ọmọ ‘Yahoo’ mẹrinlelọgbọn l’Ọwọ, oriṣiiriṣii ọkọ ni wọn ba lọwọ wọn

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ọmọ ‘Yahoo’ bii mẹrinlelọgbọn lọwọ ajọ to n gbogun ti iwa ibajẹ…

Lẹyin ọjọ mẹwaa to ti n gbaawẹ nitori ọkọ rẹ to file silẹ fọdun mẹrin, Joy ku si ṣọọṣi n’Ishẹri-Ọlọfin

Adefunkẹ Adebiyi Obinrin kan, Joy Owoẹyẹ, ẹni ti ọkọ rẹ file silẹ latọdun kẹrin sẹyin lai…

Tirela pada lasiko to n gun biriiji l’Oṣogbo, eeyan mẹjọ lo ku, ọpọ fara pa

Florence Babaṣọla Lasiko ti a n kọroyin yii, eeyan mẹjọ lo ti ku nibi ijamba ọkọ…

Ijọba Eko ni ẹsun mẹrin lawọn maa ka si Baba Ijẹṣa lẹsẹ ni kootu

Faith Adebọla, Eko Ijọba ipinlẹ Eko ti ni faili iwe ẹsun tawọn ọlọpaa lawọn ti fi…