Iyawo Tinubu gba awọn ọmọ Naijiria nimọran: Ẹ yaa pada sidii iṣẹ agbẹ

Faith Adebọla Lojuna ati wa ojutuu si ọwọngogo ọja ati ebi to gbode kan lorileede Naijiria…

Ẹyin tẹẹ fẹẹ mọ iku to pa Mohbad, esi ayẹwo ẹ ti delẹ o

Faith Adebọla O jọ pe suuru ati ireti ọlọjọ gbọọrọ tawọn ololufẹ gbajugbaja onkọrin hipọọpu to…

Wọn ti ko ‘ma-mu-gaari’ sọwọ ṣọja to gun DPO lọbẹ ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Akolo ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kwara, ni afurasi ṣọja kan, Suleiman Sidiq, wa bayii.…

Awọn akẹkọọ poli to pa ọga olotẹẹli Water View, n’llọrin, bu ṣẹkun gbaragada ni kootu

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọruu, Wẹsidee, ogunjọ, oṣu Kẹta, ọdun 2024 yii, ni igbẹjọ bẹrẹ lori awọn…

Lẹyin ti wọn ji foonu rẹ tan, awọn tọọgi tun lu Alakija pa l’Ọrẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkunrin kan ti wọn porukọ rẹ ni Jeremiah Alakija, ti ṣagbako iku ojiji…

Ọmọ ọran kan ree o, nitori ẹgbẹrun mẹrindinlogun Naira, o ṣa iya to bi iya ẹ pa

Adewale Adeoye Ọmọ ọran ni orukọ ti wọn iba maa pe ọmọkunrin kan torukọ rẹ n…

 Awọn meje foju bale-ẹjọ l’Akurẹ, nnkan ija oloro ni wọn ka mọ wọn lọwọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Nile-ẹjọ Majisireeti to kan to wa niluu Akurẹ, nipinlẹ Ondo, ni awọn meje…

Dipo ki Adeleke pese ohun amayedẹrun fawọn eeyan Ọṣun, ṣokoleeti lo n jẹ kaakiri ilu oyinbo – APC

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC), nipinlẹ Ọṣun, ti fẹsun kan ẹgbọn Gomina…

Lẹyin ọjọ mẹsan-an lakata awọn ajinigbe, oyinbo Chinese ti wọn ji gbe gbominira ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Wọn ni ẹni ti yoo royin ogun ko ni i ku sogun, ọrọ…

Awọn Ibo binu tan, wọn ti gbogbo ṣọọbu wọn pa n’llọrin, wọn lawọn o taja mọ

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kọkandinlogun, oṣu Kẹta, ọdun 2024 yii, ni awọn ontaja…

Eyi lohun ti Oluwoo ni kijọba ṣe fawọn to pa sọja ni Delta

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Latari bi awọn ọdọ ilu Okuama, nipinlẹ Delta, ṣe ran awọn ọmọ ileeṣẹ…