Sunday fun ọmọ bibi inu ẹ loyun n’Ilẹ-Oluji, ibi to ti fẹẹ ba a ṣẹ ẹ lọwọ ti tẹ ẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ọlọpaa ti fi pampẹ ofin gbe ọkunrin ẹni ọdun mejidinlọgbọn kan, Sunday Udoh, lori ẹsun gbigbiyanju ati sẹyun fun ọmọ to bi ninu ara rẹ to fun loyun. ALAROYE fidi rẹ mulẹ lati ẹnu Alukoro ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ondo, Funmilayọ Ọdunlami, pe ọwọ tẹ Udoh lọjọ …

Read More »

Idi ti Jonathan ko fi le dupo aarẹ lọdun 2023- Falana

Monisọla Saka Idi ti Jonathan ko fi le dupo aarẹ lọdun 2023- Falana Agbẹjọro to tun jẹ ajafẹtọọ ọmọniyan nipinlẹ Eko, Ọgbẹni Fẹmi Falana, ti sọ l’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, pe aarẹ ilẹ wa tẹlẹ, Goodluck Ebele Jonathan, ko le jade dupo aarẹ to n bọ lọna lọdun 2023, nitori …

Read More »
//lephaush.net/4/4998019