Gbogbo awọn oloṣelu ti wọn n ko palietiifu pamọ n fa egun sori ara wọn ni – Oluwoo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti kilọ fun gbogbo awọn…

Asẹyin ilu Isẹyin da si ija Wasiu Ayinde ati onilu rẹ tẹlẹ, Ayanlọwọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori bi onilu Wasiu Ayinde tẹlẹ, Ọgbẹni Ayankunle Ayanlọwọ, ṣe jẹ ọmọ agbegbe…

Nitori foonu, Yakubu pa Sikiru, lo ba lọọ ju oku ẹ si ṣalanga

Faith Adebọla Ọwọ awọn agbofinro ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Niger, ti tẹ afurasi ọdaran ọmọọdun mọkandinlogun kan,…

O ga o! Ọmọ ọdun mẹẹẹdogun gun ẹgbẹ ẹ pa

Monisọla Saka Abubakar Isa, ọkunrin ọmọ ọdun mẹẹẹdogun kan ti fibinu fufu rẹ sọ idile ọga…

O ma ṣe o, ọmọkunrin yii lọọ wẹ lodo, lomi ba gbe e lọ

Monisọla Saka Ọkunrin ẹya Igede, lati ipinlẹ Benue, Sunday Ogah, ti ṣe bẹẹ bomi lọ lasiko…

Wọn ti mu Adamu o, maaluu mẹtalelogun lo lọọ ji ko

Monisọla Saka Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Gombe, ti tẹ afurasi ọdaran kan, Adamu Maikudi, ẹni ọdun…

 Eedi ree o! Ibọn ọlọdẹ ṣeeṣi yin, o pa ọmọde mẹta, awọn mẹrin wa nileewosan

Adewale Adeoye Awọn ọdọmọde mẹta lo ku, awọn mẹrin mi-in fara pa yannayanna lasiko ti ibọn ọlọdẹ kan ṣeeṣi…

Iya Mohbad yari kanlẹ: Ayẹwo ẹjẹ ọmọ oloogbe ko kan araalu, ọrọ ẹbi wa ni

Adewale Adeoye Pẹlu ọrọ ti Abilekọ Abọsẹde Adeyẹmọ, iya to bi gbajumọ akọrin nni, Oloogbe Ilerioluwa Alọba, ẹni tawọn eeyan mọ si Mohbad, sọ laipẹ yii, o daju pe ọrọ ayẹwo ẹjẹ fọmọ oloogbe naa ṣi maa…

Nibi ti ọmọkunrin yii ti n mura ati se ẹran ẹlẹran to ji gbe lawọn ọlọpaa ti mu un

Adewale Adeoye Ọdọ awọn ọlọpaa agbegbe Kurikyo, nijọba ibilẹ Lafia, nipinlẹ Nasarawa, ni Ọgbẹni Mohammed Tanko, ẹni ti wọn fẹsun kan pe o lọọ ji ẹran agbo nla kan…

Wọn ti mu Balogun o, ayederu ṣọja to n faṣọ ijọba lu jibiti l’Ekoo

Adewale Adeoye Lagbegbe Isheri-Ọṣun, nipinlẹ Eko, lọwọ awọn ọlọpaa ti tẹ ayederu ṣọja kan to pe ara rẹ ni Sajẹnti Major Fẹmi Balogun, pẹlu aṣọ ijọba lọrun…

Wahab yii ma laya o, ọlọpaa lo fẹẹ ja lole ti wọn fi mu un

Adewale Adeoye Afurasi adigunjale kan, Akinjọbi Wahab, ẹni ọdun mọkandinlogun, ti ṣi iṣẹ ṣe bayii o. Ọlọpaa ti ko wọsọ…