Awọn eleyii naa jira wọn gbe, inu igbo kan ni wọn lọọ sa si

Monisọla Saka Kọmiṣanna ọlọpaa ipinlẹ Eko, Adegoke Fayọade, ti gboṣuba kare fawọn ọlọpaa ọtẹlẹmuyẹ ti wọn…

Awọn ẹlẹsin ibilẹ, aafaa nla atawọn agba wolii pade nibi eto adura ọjọ kẹjọ Olubadan to waja

 Ọlawale Ajao, Ibadan Bo ba ṣe pe bi ẹsin eeyan ṣe pọ niye to l’Ọlọrun yoo…

Gbogbo ileewe pamari ati sẹkọndiri gbọdọ ni fẹnsi ati kamẹra aṣofofo nipinlẹ Ogun -Kọmiṣanna ọlọpaa

Faith Adebọla Ọkan-o-jọkan amọran ati aba ti waye lati ro eto aabo lagbara dan-in-dan-in lawọn ileewe…

Nibi tawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun ti n ṣepade l’Oṣogbo lawọn ọlọpaa ti ko wọn

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun mẹta ni ọwọ ọlọpaa ti tẹ lagbegbe Oṣogbo bayii.…

Ọwọ ti tẹ Sodiq l’Oṣogbo, ọkada mẹta ni wọn ka mọ ọn lọwọ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọjọ gbogbo ni tole, ọjọ kan bayii ni tolohun, eyi lo ṣẹ mọ…

Abẹẹ rawọn ọmọleewe yii, niṣe ni wọn jira wọn gbe, ti wọn si n beere owo itusilẹ lọwọ obi wọn

Monisọla Saka Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ti tẹ awọn akẹkọọ meji kan, Ayọdele Balogun, ẹni…

L’Ondo, adajọ ni ki Wisdom sare lọọ lo ọdun mẹfa lẹwọn pẹlu iṣẹ aṣekara

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Kootu Majisireeti to wa niluu Ondo, nijọba ibilẹ Iwọ-Oorun Ondo, ti ni ki…

Ọwọ tẹ awọn eleyii, oriṣiiriṣii ayederu ọti ni wọn n ṣe l’Agege

Adewale Adeoye Mẹrin lara awọn ọdaran kan to jẹ pe wọn ti jingiri ninu ṣiṣe ayederu ọti waini atawọn oriṣiiriṣii ọti…

Ere agbere: Iyaale ile binu para ẹ lẹyin t’ọkọ ka ale mọ ọn lori

Adewale Adeoye O da bii pe itiju aa ti i gbọ lo mu ki iyaale ile…

Abiru ki leleyii, awọn agbebọn kọ lu mọto akero, wọn ji ero inu ẹ gbe lọ

Adewale Adeoye Odidi mọto ero kan to jẹ ti ipinlẹ Katsina, iyẹn, ‘Katsina State Transport Authority’ (KTSTA) lawọn agbebọn kan…

Lẹyin ọsẹ kan ti Olubadan waja, Makinde ṣabẹwo sawọn ẹbi ọba naa

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ọsẹ kan  ti Olubadan ilẹ Ibadan, Ọba Mohood Ọlalekan Balogun waja, Gomina…