Ọkunrin yii ma daju o, awọn alaisan to wa lọsibitu lo maa n lu ni jibiti n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Pipa ni wọn iba pa ọkunrin ẹni ogoji (40) ọdun kan, Bukọla Adewale,…

Ẹgbẹ alagbata epo ti sọrọ: O ṣi maa to ọsẹ meji si i ki ọwọngogo epo yii too rọlẹ!

Faith Adebọla Ẹgbẹ awọn alagbata epo rọbi nilẹ wa, Independent Petroleum Marketers Association of Nigeria (IPMAN),…

Egboogi oloro ni Danjuma n gbe lọ sorileede Italy tọwọ fi tẹ ẹ

Adewale Adeoye Ọdọ awọn alaṣẹ ajọ to n gbogun ti gbigbe ati lilo egboogi oloro lorileede yii, ‘National Drug Law Enforcement Agency’ (NDLEA), ẹka tipinlẹ Eko, ni…

Nitori ọdun Oro, isede yoo wa fawọn obinrin niluu Ikorodu lọjọ yii

Adewale Adeoye Ni bayii, gbogbo eto ti to pata, ọjọ kẹrindinlogun, oṣu Karun-un, ọdun 2024 yii, ni awọn oniṣẹṣe niluu Ikorodu, nipinlẹ Eko lawọn maa ṣe Oro…

Ẹ ma f’ọkan si i, ijọba Tinubu ko lagbara lati tun ọrọ-aje Naijiria yii ṣe o – Suswam

Faith Adebọla Gomina tẹlẹri nipinlẹ Benue, Sẹnetọ Gabriel Suswam, ti sọ oju abẹ nikoo lori iṣejọba…

Ortom gba Yahaya Bello nimọran: Jade sita nibi to o ba wa, yee doju ti awa gomina

Faith Adebọla  Owe ẹru kan ni i mu’ni bu igba ẹru ti Yoruba maa n pa…

 Awọn agbebọn ji baba ati ọmọ gbe lọ ni Ọ̀sẹ́

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọmọkunrin kan to jẹ akẹkọọ ileewe girama awọn ọmọ ogun oju ofurufu to…

Awọn araalu pariwo l’Ọṣun: Iya yii ti pọ ju, ṣe lawọn elepo mọ-ọn-mọ n gbe e pamọ o

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn eeyan ipinlẹ Ọṣun ti kegbajare sijọba Gomina Ademọla Adeleke lati tete gbe…

Awọn ọrẹ mẹta ṣe ‘kinni’ fun ọmọbinrin kan ti ha o, adajọ ti ni ki wọn maa ko wọn lọ sọgba ẹwọn

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ile-ẹjọ Majisireeti kan to filu Ilọrin, nipinlẹ Kwara, ṣebujokoo, ti paṣẹ pe ki…

Finidi George di akọni-mọ-ọn-gba tuntun fun Super Eagles

Faith Adebọla  Ni bayii, ṣinkin bii ẹni jẹ tẹtẹ oriire ni inu gbajumọ agbabọọlu ilẹ wa…

Dare niyawo oun n yan ale, lo ba gun un pa l’Ado-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti  Iyanu nla lo jẹ loju gbogbo eeyan ilu Ado-Ekiti, nirọlẹ ọjọ Abamẹta, Satide,…