Nnkan de! Aṣẹwo wọ Mọrufu lọ si kootu, o lo ji owo oun

Florence Babaṣọla Yinkun yinkun ti Sikiru Mọrufu, ẹni ọdun mejidinlọgbọn, ṣe fun obinrin aṣẹwo kan ti…

Sọlihu pariwo nile-ẹjọ : Emi kọ ni mo ni oyun inu Kẹhinde, o fẹẹ ti i mọ mi lọrun ni o

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Iwaju Onidaajọ AbdulQadir Umar, to jẹ adajọ ile-ẹjọ kọkọ-kọkọ kan ti wọn n…

Emi l’Akeredolu fontẹ lu gẹgẹ bii ẹni to maa di gomina lẹyin rẹ ko too ku- Ayedatiwa

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina Lucky Orimisan Ayedatiwa ti ni ọga oun, iyẹn Oloogbe Rotimi Akeredolu, ti…

O ṣẹlẹ, ileewe ti wọn ti n kọ ẹkọ nipa Yahoo lọwọ EFCC ti tẹ awọn eleyii

Ibrahim Alagunmu Afi bii ẹni pe ajọ to n gbogun ti iwa jibiti ati ṣiṣe owo…

Ijọba ṣawari mọṣuari tawọn agbenipa n gbe oku si n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọbọ, Tọsidee, ọjọ kẹẹẹdogun, oṣu Keji yii, ni ijọba ipinlẹ Kwara, ti mọsuari…

Nitori owo tikẹẹti, agbero fun onikẹkẹ lọrun pa

Monisọla Saka Ọkan lara awọn agbero to n jawe fawọn onimọto ati ọlọkada nipinlẹ Delta, Task…

Ọga ọlọpaa kowo jẹ, wọn ti yọ ọ bii jiga nipo

Monisọla Saka Kọmiṣanna ọlọpaa ipinlẹ Delta, CP Abaniwọnda Olufẹmi, ti paṣẹ pe ki wọn gbọn SP…

Nitori iṣẹlẹ ijinigbe ojoojumọ, ibẹru gb’ọkan awọn eeyan Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Inu ibẹru nla lawọn eeyan Akoko ati Ọwọ, eyi to wa lẹkun Ariwa…

Ijọba pin nnkan ija loriṣiiriṣii fawọn ẹṣọ alaabo l’Ekiti

 Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ni ilakaka ijọba ipinlẹ Ekiti lati fi opin si eto ijinigbe ati iṣeku…

Gomina Ayedatiwa gba awọn ọba Yoruba nimọran

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina ipinlẹ Ondo, Ọnarebu Lucky Orimisan Ayedatiwa, ti gba awọn ọba ilẹ Yoruba…

Tinubu, awọn gomina fọwọ si idasilẹ ọlọpaa ipinlẹ

Jọkẹ Amọri Nibi ipade pajawiri kan ti ijọba apapọ ati awọn gomina kaakiri ipinlẹ mẹrẹẹrindinlogoji to…