Awọn agbebọn ji Baalẹ Apanpa atiyawo rẹ gbe lọ labule kan n’Ibadan

Titi di ba  a ṣe n sọ yii ni awọn ara abule ṣi n wa Baale…

 Ọwọ tẹ tọkọ-tiyawo to n gbe egboogi oloro ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Ajọ to n gbogun ti asilo oogun ati egbogi oloro ni ilẹ yii,…

Awọn agbebọn to wa ninu igbo lagbegbe Ariwa/Iwọ-Oorun ju ẹgbẹrun lọna ọgọrun-un lọ-Gumi

Faith Adebọla Ilu-mọ-ọn-ka aṣaaju ẹsin Musulumi l’Oke-Ọya nni, Sheik Abubakar Gumi, ti sọ pe ọna kan…

Tori wọn yinbọn fawọn maaluu to n jẹko lagbegbe wọn, ọlọpaa ju awọn ọdọ mẹta sahaamọ l’Eruwa

Faith Adebọla  Ahamọ ọlọpaa ipinlẹ Ọyọ lawọn ọdọ mẹta ọmọ bibi ilu Eruwa yii, Ọpẹyẹmi Ajibọdun,…

Eyi ni bi owo Ọtẹdọla ṣe ran aṣofin ilẹ wa kan lewọn ọdun meje

Ṣe ẹ ranti Ọnarebu Farouk Lawan, aṣoju-ṣofin ilẹ wa tẹlẹ ri lati ipinlẹ Kano fun saa…

Nitori oko oloko ti Gabriel lọọ fina si l’Ekiti, adajọ ti ran an lẹwọn

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ọmọdekunrin ẹni ọdun mẹtalelogun kan, Ode Gabriel, ni ile-ẹjọ kan to wa ni…

Ijọba Eko ṣofin irinna tuntun ati ijiya nla fawọn to ba rufin

Faith Adebọla, Eko Ijọba ipinlẹ Eko ti fihan pe wiwakọ lai bofin mu nipinlẹ Eko ki…

Ọmọọdọ atọmọ ti Kinsley bi ninu ara ẹ lo n ba laṣepọ ni Festac

Faith Adebọla, Eko Agbọ-ṣe-haa lọrọ ọhun, afi bii ere ori itage, ṣugbọn iṣẹlẹ to waye gidi…

Awọn agbebọn pa ọkan ninu awọn oloye ẹgbẹ APC n’Ifọn

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹgbẹ APC ipinlẹ Ondo ti kẹdun iku ọkan ninu awọn oloye ẹgbẹ ọhun,…

Baba Ijẹṣa maa pada sile-ẹjọ l’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii

Faith Adebọla, Eko Ọjọbọ, Tọsidee, to n bọ yii, ni gbajugbaju adẹrin-in poṣonu ilẹ wa nni,…

Ọlọpaa n wa mọlẹbi ọmọbinrin ti wọn ba oku ẹ lotẹẹli kan ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilorin Ọmọbinrin kan ti wọn ko ti i mọ ibi to ti wa, ni…