Ṣeun Kuti ju bọmbu ọrọ: Bo ba jẹ ọmọ olowo lẹ fun loyun, ṣe ẹ maa sọ pe ẹ fẹẹ ṣe ayẹwo ẹjẹ (DNA)

Monisọla Saka Olorin taka-sufee ilẹ wa to jẹ ọmọ bibi inu Fẹla Anikulapo Kuti, ti i…

Aye le o: Wọn di oku ọmọkunrin kan sinu apo, wọn si gbe e sidii ọgẹdẹ n’Iyin-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Kayeefi nla lo jẹ fun gbogbo eeyan ilu Iyin-Ekiti, nijọba ibilẹ Irepọdun/Ifẹlodun, nipinlẹ…

Ajalu buruku! Igbakeji kọmiṣanna ọlọpaa Eko pokunso

  Adewale Adeoye Titi di asiko ta a n koroyin yii jọ lọwọ lọrọ iku igbakeji Kọmiṣanna ọlọpaa nipinlẹ Eko, Oloogbe D.C.P Gbolahan Oyedemi, to…

Awọn agbebọn yinbọn mọ oni POS lẹyin ti wọn gbowo ati foonu rẹ l”Ado-Ekiti 

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti  Ipaya ati aibalẹ ọkan, eyi to mu ki awọn eeyan maa sa kijokijo…

Awọn araalu ya bo tirela to ko ounjẹ l’Akurẹ, ni wọn ba ko gbogbo ẹ lọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Iṣoro ọwọngogo ounjẹ to n b’awọn araalu finra tun gbọna mi-in yọ lọjọ…

Gbogbo awọn oloṣelu ti wọn n ko palietiifu pamọ n fa egun sori ara wọn ni – Oluwoo

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi, ti kilọ fun gbogbo awọn…

Asẹyin ilu Isẹyin da si ija Wasiu Ayinde ati onilu rẹ tẹlẹ, Ayanlọwọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori bi onilu Wasiu Ayinde tẹlẹ, Ọgbẹni Ayankunle Ayanlọwọ, ṣe jẹ ọmọ agbegbe…

Nitori foonu, Yakubu pa Sikiru, lo ba lọọ ju oku ẹ si ṣalanga

Faith Adebọla Ọwọ awọn agbofinro ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Niger, ti tẹ afurasi ọdaran ọmọọdun mọkandinlogun kan,…

O ga o! Ọmọ ọdun mẹẹẹdogun gun ẹgbẹ ẹ pa

Monisọla Saka Abubakar Isa, ọkunrin ọmọ ọdun mẹẹẹdogun kan ti fibinu fufu rẹ sọ idile ọga…

O ma ṣe o, ọmọkunrin yii lọọ wẹ lodo, lomi ba gbe e lọ

Monisọla Saka Ọkunrin ẹya Igede, lati ipinlẹ Benue, Sunday Ogah, ti ṣe bẹẹ bomi lọ lasiko…

Wọn ti mu Adamu o, maaluu mẹtalelogun lo lọọ ji ko

Monisọla Saka Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Gombe, ti tẹ afurasi ọdaran kan, Adamu Maikudi, ẹni ọdun…